سورة البينة باليوربا
Awon t’o sai gbagbo ninu awon ahlul-kitab ati awon osebo, won ko nii kuro ninu aigbagbo won titi di igba ti eri t’o yanju yo fi maa de odo won |
Ojise kan lati odo Allahu yo (si) maa ke awon takada mimo |
Awon iwe ofin t’o fese rinle si wa ninu re |
وَمَا تَفَرَّقَ الَّذِينَ أُوتُوا الْكِتَابَ إِلَّا مِن بَعْدِ مَا جَاءَتْهُمُ الْبَيِّنَةُ(4) Awon ti A fun ni tira ko si di ijo otooto afi leyin ti eri t’o yanju de ba won |
Awa ko si pa won ni ase kan bi ko se pe ki won josin fun Allahu (ki won je) oluse-afomo esin fun Un, oluduro deede. Ki won kirun, ki won si yo Zakah. Iyen si ni esin t’o fese rinle |
Dajudaju awon t’o sai gbagbo (wonyi) ninu awon ahlul-kitab ati awon osebo, won yoo wa ninu Ina. Olusegbere ni won ninu re. Awon wonyen, awon ni eda t’o buru julo |
إِنَّ الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ أُولَٰئِكَ هُمْ خَيْرُ الْبَرِيَّةِ(7) Dajudaju awon t’o gbagbo ni ododo (iyen, awon musulumi), ti won si se awon ise rere, awon wonyen, awon ni eda t’o dara julo |
Esan won ni odo Oluwa won ni awon Ogba Idera gbere, ti awon odo n san ni isale re. Olusegbere ni won ninu re titi laelae. Allahu yonu si won. Awon naa yonu si (ohun ti Allahu fun won). Iyen wa fun enikeni ti o ba paya Oluwa re |
المزيد من السور باللغة اليوربا:
تحميل سورة البينة بصوت أشهر القراء :
قم باختيار القارئ للاستماع و تحميل سورة البينة كاملة بجودة عالية
أحمد العجمي
خالد الجليل
سعد الغامدي
سعود الشريم
عبد الباسط
عبد الله الجهني
علي الحذيفي
فارس عباد
ماهر المعيقلي
محمد جبريل
المنشاوي
الحصري
مشاري العفاسي
ناصر القطامي
ياسر الدوسري
Sunday, December 22, 2024
لا تنسنا من دعوة صالحة بظهر الغيب