Перевод суры Аль-Джинн на Йоруба язык
So pe: "Won fi imisi ranse si mi pe dajudaju ijo kan ninu awon alujannu teti (si al-Ƙur’an)." Won si so pe: "Dajudaju awa gbo al-Ƙur’an iyanu |
يَهْدِي إِلَى الرُّشْدِ فَآمَنَّا بِهِ ۖ وَلَن نُّشْرِكَ بِرَبِّنَا أَحَدًا(2) O n setosona sibi imona. Nitori naa, a gba a gbo. Awa ko si nii fi eni kan kan se akegbe fun Oluwa wa |
وَأَنَّهُ تَعَالَىٰ جَدُّ رَبِّنَا مَا اتَّخَذَ صَاحِبَةً وَلَا وَلَدًا(3) Ati pe dajudaju titobi Oluwa wa ga. Ko fi eni kan kan se aya ati omo |
Dajudaju omugo ninu wa maa n so isokuso nipa Allahu |
وَأَنَّا ظَنَنَّا أَن لَّن تَقُولَ الْإِنسُ وَالْجِنُّ عَلَى اللَّهِ كَذِبًا(5) Dajudaju awa si n ro pe eniyan ati alujannu ko nii pa iro mo Allahu ni |
وَأَنَّهُ كَانَ رِجَالٌ مِّنَ الْإِنسِ يَعُوذُونَ بِرِجَالٍ مِّنَ الْجِنِّ فَزَادُوهُمْ رَهَقًا(6) Ati pe dajudaju awon okunrin kan ninu eniyan maa n fi awon okunrin kan ninu awon alujannu wa aabo. Awon alujannu si se alekun aburu fun won |
وَأَنَّهُمْ ظَنُّوا كَمَا ظَنَنتُمْ أَن لَّن يَبْعَثَ اللَّهُ أَحَدًا(7) Dajudaju awon alujannu lero gege bi eyin eniyan naa se lero pe Allahu ko nii gbe eni kan kan dide (leyin iku) |
وَأَنَّا لَمَسْنَا السَّمَاءَ فَوَجَدْنَاهَا مُلِئَتْ حَرَسًا شَدِيدًا وَشُهُبًا(8) Dajudaju awa wa (oro ayogbo) wa si sanmo, a si ba a ti o ti kun fun awon eso t’o lagbara ati awon ogunna |
Dajudaju awa maa n jokoo sibe ni awon ibudo kan fun gbigbo oro. Sugbon eni t’o ba joro gbo lasiko yii, o maa ri ogunna t’o ti lugo de e |
وَأَنَّا لَا نَدْرِي أَشَرٌّ أُرِيدَ بِمَن فِي الْأَرْضِ أَمْ أَرَادَ بِهِمْ رَبُّهُمْ رَشَدًا(10) Dajudaju awa ko si mo boya aburu ni won gba lero pelu awon t’o wa lori ile tabi Oluwa won gbero imona fun won |
وَأَنَّا مِنَّا الصَّالِحُونَ وَمِنَّا دُونَ ذَٰلِكَ ۖ كُنَّا طَرَائِقَ قِدَدًا(11) Dajudaju awon eni rere wa ninu wa. Awon miiran yato si iyen tun wa ninu wa. A wa loju ona (esin) otooto |
وَأَنَّا ظَنَنَّا أَن لَّن نُّعْجِزَ اللَّهَ فِي الْأَرْضِ وَلَن نُّعْجِزَهُ هَرَبًا(12) Dajudaju awa mo amodaju pe awa ko le mori bo mo Allahu lowo lori ile. Awa ko si le sa mo On lowo |
Dajudaju nigba ti a gbo nipa imona (lati inu al-Ƙur’an), a gba a gbo. Nitori naa, enikeni ti o ba gba Oluwa re gbo, ki o ma beru adinku (esan rere) ati (alekun) aburu |
Dajudaju awon musulumi wa ninu wa. Awon arufin naa wa ninu wa. Nitori naa, enikeni ti o ba se ’Islam, awon wonyen ni won se awari imona |
Ni ti awon arufin, awon ni won maa je igi ikona fun ina Jahanamo.” |
وَأَن لَّوِ اسْتَقَامُوا عَلَى الطَّرِيقَةِ لَأَسْقَيْنَاهُم مَّاءً غَدَقًا(16) Ati pe ti o ba je pe won duro sinsin loju ona (’Islam) ni, dajudaju Awa iba fun won ni omi pupo mu |
لِّنَفْتِنَهُمْ فِيهِ ۚ وَمَن يُعْرِضْ عَن ذِكْرِ رَبِّهِ يَسْلُكْهُ عَذَابًا صَعَدًا(17) Nitori ki A le fi dan won wo ni. Enikeni ti o ba gbunri kuro nibi iranti Oluwa re, O maa mu un wo inu iya inira |
وَأَنَّ الْمَسَاجِدَ لِلَّهِ فَلَا تَدْعُوا مَعَ اللَّهِ أَحَدًا(18) Dajudaju awon mosalasi n je ti Allahu. Nitori naa, e o gbodo fi pe eni kan pelu Allahu |
وَأَنَّهُ لَمَّا قَامَ عَبْدُ اللَّهِ يَدْعُوهُ كَادُوا يَكُونُونَ عَلَيْهِ لِبَدًا(19) Dajudaju nigba ti erusin Allahu dide duro t’o n pe Allahu, awon alujannu fee maa difun-un-unfun lodo re (lati teti si al-Ƙur’an) |
قُلْ إِنَّمَا أَدْعُو رَبِّي وَلَا أُشْرِكُ بِهِ أَحَدًا(20) So pe: "Oluwa mi ni mo n pe. Ati pe emi ko nii so eni kan kan di akegbe fun Un |
So pe: "Dajudaju emi ko ni ikapa lori inira ati imona fun yin |
قُلْ إِنِّي لَن يُجِيرَنِي مِنَ اللَّهِ أَحَدٌ وَلَنْ أَجِدَ مِن دُونِهِ مُلْتَحَدًا(22) So pe: "Dajudaju emi, ko si eni kan t’o le gba mi la lodo Allahu. Emi ko si ri ibusasi kan leyin Re |
Afi (ki ng se) ikede (t’o wa) lati odo Allahu ati awon ise Re (t’O fi ran mi). Enikeni t’o ba yapa Allahu ati Ojise Re, dajudaju ina Jahanamo n be fun un. Olusegbere ni won ninu re titi laelae |
حَتَّىٰ إِذَا رَأَوْا مَا يُوعَدُونَ فَسَيَعْلَمُونَ مَنْ أَضْعَفُ نَاصِرًا وَأَقَلُّ عَدَدًا(24) (Alaigbagbo ko nii ye sai gbagbo) titi di igba ti won yoo fi ri ohun ti A n se ni adehun fun won. Nigba naa, won yoo mo ta ni o le julo ni alaranse, ti o si kere julo ni onka |
قُلْ إِنْ أَدْرِي أَقَرِيبٌ مَّا تُوعَدُونَ أَمْ يَجْعَلُ لَهُ رَبِّي أَمَدًا(25) So pe: "Emi ko mo boya ohun ti Won n se ni adehun fun yin ti sunmo tabi Oluwa mi yoo fun un ni akoko (t’o jinna) |
عَالِمُ الْغَيْبِ فَلَا يُظْهِرُ عَلَىٰ غَيْبِهِ أَحَدًا(26) Onimo-ikoko, ko si fi (imo) ikoko Re han eni kan |
إِلَّا مَنِ ارْتَضَىٰ مِن رَّسُولٍ فَإِنَّهُ يَسْلُكُ مِن بَيْنِ يَدَيْهِ وَمِنْ خَلْفِهِ رَصَدًا(27) ayafi eni ti O salesa t’o je Ojise. Dajudaju O n mu eso kan rin niwaju Ojise naa ati leyin re |
nitori ki O le safi han pe won ti je awon ise Oluwa won. Ati pe Allahu fi imo rokiri ka ohun ti n be lodo won. O si so onka gbogbo nnkan |
Больше сур в Йоруба:
Скачать суру Al-Jinn с голосом самых известных рекитаторов Корана:
Сура Al-Jinn mp3: выберите рекитатора, чтобы прослушать и скачать главу Al-Jinn полностью в высоком качестве
Ahmed Al Ajmy
Bandar Balila
Khalid Al Jalil
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdul Rashid Sufi
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Yasser Al Dosari
Помолитесь за нас хорошей молитвой