سورة نوح باليوربا
Dajudaju Awa ran (Anabi) Nuh nise si ijo re pe: "Sekilo fun ijo re siwaju ki iya eleta-elero to de ba won |
O so pe: "Eyin ijo mi, dajudaju emi ni olukilo ponnbele fun yin |
pe ki e josin fun Allahu, ki e beru Re, ki e si tele mi |
(Allahu) maa saforijin awon ese yin fun yin. O si maa lo yin lara titi di gbedeke akoko kan. Dajudaju akoko (iku ti) Allahu (ko mo eda), nigba ti o ba de, won ko nii sun un siwaju ti o ba je pe e mo |
O so pe: "Oluwa mi, dajudaju emi pe ijo mi ni oru ati ni osan |
Ipe mi ko si se alekun kan fun won ayafi sisa seyin (fun ododo) |
Ati pe igbakigba ti mo ba pe won pe ki O le forijin won, won n fi omonika won di eti won, won n yiso won bori, won n taku (sori ese), won si n segberaga gan-an |
Leyin naa, dajudaju emi pe won pelu ohun oke |
ثُمَّ إِنِّي أَعْلَنتُ لَهُمْ وَأَسْرَرْتُ لَهُمْ إِسْرَارًا(9) Leyin naa, dajudaju emi kede fun won, mo si tun pe won ni ida konko |
فَقُلْتُ اسْتَغْفِرُوا رَبَّكُمْ إِنَّهُ كَانَ غَفَّارًا(10) Mo si so pe, e toro aforijin ni odo Oluwa yin, dajudaju O n je Alaforijin |
O maa rojo fun yin ni ojo pupo |
وَيُمْدِدْكُم بِأَمْوَالٍ وَبَنِينَ وَيَجْعَل لَّكُمْ جَنَّاتٍ وَيَجْعَل لَّكُمْ أَنْهَارًا(12) O maa fi awon dukia ati awon omokunrin ran yin lowo. O maa se awon ogba oko fun yin. O si maa se awon odo fun yin |
Ki lo mu yin ti e ko paya titobi Allahu |
O si kuku seda yin lati irisi kan si omiran (ninu oyun) |
أَلَمْ تَرَوْا كَيْفَ خَلَقَ اللَّهُ سَبْعَ سَمَاوَاتٍ طِبَاقًا(15) Se e o ri bi Allahu se da awon sanmo meje ni ipele ipele ni |
وَجَعَلَ الْقَمَرَ فِيهِنَّ نُورًا وَجَعَلَ الشَّمْسَ سِرَاجًا(16) O si se osupa ni imole sinu won. O tun se oorun ni atupa |
Allahu mu yin jade lati ara erupe ile |
Leyin naa, O maa da yin pada sinu re. O si maa mu yin jade taara |
Allahu se ile fun yin ni ite |
nitori ki e le to awon oju ona fife gbegede lori re |
(Anabi) Nuh so pe: "Oluwa mi, dajudaju won yapa mi. Won si tele eni ti dukia re ati omo re ko se alekun kan fun bi ko se ofo |
Won si dete ni ete t’o tobi |
Won si wi pe: "E ma se fi awon orisa yin sile. E ma se fi orisa Wadd, Suwa‘u, Yeguth, Ye‘uƙ ati Nasr sile |
وَقَدْ أَضَلُّوا كَثِيرًا ۖ وَلَا تَزِدِ الظَّالِمِينَ إِلَّا ضَلَالًا(24) Dajudaju won ti ko opolopo sina. (Oluwa mi) ma se je ki awon alabosi lekun ni kini kan bi ko se isina |
Nitori ese won, won te won ri sinu omi. Won si maa fi won sinu Ina. Won ko si nii ri awon alaranse fun won leyin Allahu |
وَقَالَ نُوحٌ رَّبِّ لَا تَذَرْ عَلَى الْأَرْضِ مِنَ الْكَافِرِينَ دَيَّارًا(26) (Anabi) Nuh tun so pe: "Oluwa mi, ma se fi eni kan kan ninu awon alaigbagbo sile lori ile |
إِنَّكَ إِن تَذَرْهُمْ يُضِلُّوا عِبَادَكَ وَلَا يَلِدُوا إِلَّا فَاجِرًا كَفَّارًا(27) Dajudaju ti Iwo ba fi won sile, won yoo ko isina ba awon eru Re. Won ko si nii bi omo kan afi eni buruku, alaigbagbo |
Oluwa mi forijin emi, awon obi mi mejeeji ati eni t’o ba wo inu ile mi (ti o je) onigbagbo ododo ati awon onigbagbo ododo lokunrin ati onigbagbo ododo lobinrin. Ma si salekun kan fun awon alabosi afi iparun |
المزيد من السور باللغة اليوربا:
تحميل سورة نوح بصوت أشهر القراء :
قم باختيار القارئ للاستماع و تحميل سورة نوح كاملة بجودة عالية
أحمد العجمي
خالد الجليل
سعد الغامدي
سعود الشريم
عبد الباسط
عبد الله الجهني
علي الحذيفي
فارس عباد
ماهر المعيقلي
محمد جبريل
المنشاوي
الحصري
مشاري العفاسي
ناصر القطامي
ياسر الدوسري
Monday, November 4, 2024
لا تنسنا من دعوة صالحة بظهر الغيب