Surah Al-Masad with Yoruba
Owo Abu-Lahab mejeeji ti sofo. Oun naa si sofo |
Awon dukia re ati ohun ti o se nise (iyen, awon omo re) ko si nii ro o loro (nibi iya) |
O si maa wo inu Ina elejo fofo |
Ati iyawo re, alaaaru-igi-isepe elegun-un, (o maa wona) |
Igba-ope ponponran maa wa ni orun re (ninu Ina) |
More surahs in Yoruba:
Download surah Al-Masad with the voice of the most famous Quran reciters :
surah Al-Masad mp3 : choose the reciter to listen and download the chapter Al-Masad Complete with high quality
Ahmed Al Ajmy
Bandar Balila
Khalid Al Jalil
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdul Rashid Sufi
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Yasser Al Dosari
لا تنسنا من دعوة صالحة بظهر الغيب