Surah Al-Humazah with Yoruba
Egbe ni fun gbogbo abuniloju-eni, abunileyin-eni |
eni ti o ko owo jo, ti o si ka a lakatunka (lai na an fesin) |
O n lero pe dajudaju dukia re yoo mu un se gbere (nile aye) |
Rara (ko ri bee). Dajudaju won maa ku u loko sinu Hutomoh ni |
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Hutomoh |
(Ohun ni) Ina Allahu ti won n ko (t’o n jo geregere) |
eyi ti o maa jo (eda) wo inu okan lo |
Dajudaju won maa ti (awon ilekun) Ina pa mo won lori patapata |
(Won maa wa) laaarin awon opo kiribiti giga (ninu Ina) |
More surahs in Yoruba:
Download surah Al-Humazah with the voice of the most famous Quran reciters :
surah Al-Humazah mp3 : choose the reciter to listen and download the chapter Al-Humazah Complete with high quality
Ahmed Al Ajmy
Bandar Balila
Khalid Al Jalil
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdul Rashid Sufi
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Yasser Al Dosari
لا تنسنا من دعوة صالحة بظهر الغيب