Surah Ad-Dhuha with Yoruba
وَالضُّحَىٰ(1) (Allahu bura pelu) iyaleta |
O tun bura pelu ale nigba ti (ile) ba su |
Oluwa re ko pa o ti, ko si binu si o |
Dajudaju orun loore fun o ju aye lo |
Dajudaju laipe Oluwa re maa fun o ni (oore pupo ni orun). Nitori naa, o si maa yonu si i |
Se (Allahu) ko ri o ni omo-orukan ni? O si fun o ni ibugbe |
O si ri o ni alaimona (iyen siwaju isokale imisi). O si fi ona mo o |
O tun ri o ni alaini, O si ro o loro |
Nitori naa, ni ti omo-orukan, ma se je gaba (le e lori) |
Ni ti alagbe, ma si se jagbe (mo on) |
Ni ti idera Oluwa re, so o jade |
More surahs in Yoruba:
Download surah Ad-Dhuha with the voice of the most famous Quran reciters :
surah Ad-Dhuha mp3 : choose the reciter to listen and download the chapter Ad-Dhuha Complete with high quality
Ahmed Al Ajmy
Bandar Balila
Khalid Al Jalil
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdul Rashid Sufi
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Yasser Al Dosari
لا تنسنا من دعوة صالحة بظهر الغيب