سورة القمر باليوربا
Akoko naa sunmo. Osupa si la peregede (si meji) |
وَإِن يَرَوْا آيَةً يُعْرِضُوا وَيَقُولُوا سِحْرٌ مُّسْتَمِرٌّ(2) Ti won ba ri ami kan, won maa gbunri. Won yo si wi pe: "Idan kan (t’o lagbara) t’o maa lo ni |
وَكَذَّبُوا وَاتَّبَعُوا أَهْوَاءَهُمْ ۚ وَكُلُّ أَمْرٍ مُّسْتَقِرٌّ(3) Won pe e niro. Won si tele ife-inu won. Gbogbo ise eda si maa jokoo ti i lorun |
Dajudaju eyi ti won fi ohun lile ko wa ninu awon iro t’o de ba won |
Ijinle oye t’o peye ni; sugbon awon ikilo naa ko ro won loro |
فَتَوَلَّ عَنْهُمْ ۘ يَوْمَ يَدْعُ الدَّاعِ إِلَىٰ شَيْءٍ نُّكُرٍ(6) Seri kuro ni odo won. Ni ojo ti olupepe yoo pepe fun kini kan ti emi korira (iyen, Ajinde) |
خُشَّعًا أَبْصَارُهُمْ يَخْرُجُونَ مِنَ الْأَجْدَاثِ كَأَنَّهُمْ جَرَادٌ مُّنتَشِرٌ(7) Oju won maa wale ni ti abuku. Won yo si maa jade lati inu saree bi eni pe esu ti won fonka sita ni won |
مُّهْطِعِينَ إِلَى الدَّاعِ ۖ يَقُولُ الْكَافِرُونَ هَٰذَا يَوْمٌ عَسِرٌ(8) Won yo si maa yara lo si odo olupepe naa. Awon alaigbagbo yo si wi pe: "Eyi ni ojo isoro |
۞ كَذَّبَتْ قَبْلَهُمْ قَوْمُ نُوحٍ فَكَذَّبُوا عَبْدَنَا وَقَالُوا مَجْنُونٌ وَازْدُجِرَ(9) Ijo (Anabi) Nuh pe ododo niro siwaju won. Nigba naa, won pe erusin Wa ni opuro. Won si wi pe: "Were ni." Won si ko fun un pelu ohun lile. won fi ohun lile ko ododo sile fun Anabi Nuh (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) ni kiko alesa-seyin fun won nipase siso oro buruku si i hihale mo on |
Nitori naa, o pe Oluwa re pe: "Dajudaju won ti bori mi. Ran mi lowo |
Nitori naa, A si awon ilekun sanmo sile pelu omi t’o lagbara |
وَفَجَّرْنَا الْأَرْضَ عُيُونًا فَالْتَقَى الْمَاءُ عَلَىٰ أَمْرٍ قَدْ قُدِرَ(12) A tun mu awon odo seyo lori ile. Omi (sanmo) pade (omi ile) pelu ase ti A ti ko (le won lori) |
A si gbe (Anabi) Nuh gun oko onipako, oko elesoo |
t’o n rin (lori omi) loju Wa. (O je) esan fun eni ti won tako |
Dajudaju A fi sile ni ami. Nje oluranti wa bayii bi |
Bawo ni iya Mi ati ikilo Mi ti ri na (lara won) |
وَلَقَدْ يَسَّرْنَا الْقُرْآنَ لِلذِّكْرِ فَهَلْ مِن مُّدَّكِرٍ(17) Dajudaju A se al-Ƙur’an ni irorun fun sise iranti. Nje oluranti wa bayii bi |
Iran ‘Ad pe ododo niro. Bawo ni iya Mi ati ikilo Mi ti ri na (lara won) |
إِنَّا أَرْسَلْنَا عَلَيْهِمْ رِيحًا صَرْصَرًا فِي يَوْمِ نَحْسٍ مُّسْتَمِرٍّ(19) Dajudaju Awa ran ategun lile si won ni ojo buruku kan t’o n te siwaju |
تَنزِعُ النَّاسَ كَأَنَّهُمْ أَعْجَازُ نَخْلٍ مُّنقَعِرٍ(20) O n fa awon eniyan jade bi eni pe kukute igi ope ti won fa tu tegbotegbo ni won |
Bawo ni iya Mi ati ikilo Mi ti ri na (lara won) |
وَلَقَدْ يَسَّرْنَا الْقُرْآنَ لِلذِّكْرِ فَهَلْ مِن مُّدَّكِرٍ(22) Dajudaju A se al-Ƙur’an ni irorun fun sise iranti. Nje oluranti wa bayii bi |
Ijo Thamud pe awon ikilo niro |
فَقَالُوا أَبَشَرًا مِّنَّا وَاحِدًا نَّتَّبِعُهُ إِنَّا إِذًا لَّفِي ضَلَالٍ وَسُعُرٍ(24) Won wi pe: "Se abara kan, eni kan soso ninu wa ni a oo maa tele. (Bi o ba ri bee) nigba naa dajudaju awa ti wa ninu isina ati iya |
أَأُلْقِيَ الذِّكْرُ عَلَيْهِ مِن بَيْنِنَا بَلْ هُوَ كَذَّابٌ أَشِرٌ(25) Se oun ni won so iranti kale fun laaarin wa? Rara o, opuro onigbeeraga ni |
Ni ola ni won yoo mo ta ni opuro onigbeeraga |
إِنَّا مُرْسِلُو النَّاقَةِ فِتْنَةً لَّهُمْ فَارْتَقِبْهُمْ وَاصْطَبِرْ(27) Dajudaju Awa maa ran abo rakunmi si won; (o maa je) adanwo fun won. Nitori naa, maa wo won niran na, ki o si se suuru |
وَنَبِّئْهُمْ أَنَّ الْمَاءَ قِسْمَةٌ بَيْنَهُمْ ۖ كُلُّ شِرْبٍ مُّحْتَضَرٌ(28) Ki o si fun won ni iro pe dajudaju pipin ni omi laaarin won. Gbogbo ipin omi si wa fun eni ti o ba kan lati wa si odo |
Nigba naa ni won pe eni won. O wa ona lati mu (rakunmi naa mole). O si pa a |
Bawo ni iya Mi ati ikilo Mi ti ri na (lara won) |
إِنَّا أَرْسَلْنَا عَلَيْهِمْ صَيْحَةً وَاحِدَةً فَكَانُوا كَهَشِيمِ الْمُحْتَظِرِ(31) Dajudaju Awa ran igbe kan soso si won. Won si da bi igi koriko gbigbe |
وَلَقَدْ يَسَّرْنَا الْقُرْآنَ لِلذِّكْرِ فَهَلْ مِن مُّدَّكِرٍ(32) Dajudaju A se al-Ƙur’an ni irorun fun sise iranti. Nje oluranti wa bayii bi |
Ijo Lut pe awon ikilo niro |
إِنَّا أَرْسَلْنَا عَلَيْهِمْ حَاصِبًا إِلَّا آلَ لُوطٍ ۖ نَّجَّيْنَاهُم بِسَحَرٍ(34) Dajudaju Awa fi okuta ina ranse si won afi ara ile Lut, ti A gbala ni asiko saari |
(O je) ike kan lati odo Wa. Bayen ni A se n san esan fun eni t’o ba dupe (fun Wa) |
وَلَقَدْ أَنذَرَهُم بَطْشَتَنَا فَتَمَارَوْا بِالنُّذُرِ(36) O kuku fi igbamu Wa se ikilo fun won, sugbon won ja awon ikilo niyan |
وَلَقَدْ رَاوَدُوهُ عَن ضَيْفِهِ فَطَمَسْنَا أَعْيُنَهُمْ فَذُوقُوا عَذَابِي وَنُذُرِ(37) Won kuku lakaka lodo re lati ba awon alejo re sebaje. Nitori naa, A fo oju won. E to iya Mi ati ikilo Mi wo |
Ati pe dajudaju iya gbere ni won mojumo sinu re ni owuro kutukutu |
Nitori naa, e to iya Mi ati ikilo Mi wo |
وَلَقَدْ يَسَّرْنَا الْقُرْآنَ لِلذِّكْرِ فَهَلْ مِن مُّدَّكِرٍ(40) Dajudaju A se al-Ƙur’an ni irorun fun sise iranti. Nje oluranti wa bayii bi |
Dajudaju awon ikilo de ba awon eniyan Fir‘aon |
كَذَّبُوا بِآيَاتِنَا كُلِّهَا فَأَخَذْنَاهُمْ أَخْذَ عَزِيزٍ مُّقْتَدِرٍ(42) Won pe awon ayah Wa niro, gbogbo re patapata. A si gba won mu ni igbamu (ti) Alagbara, Olukapa (n gba eda mu) |
أَكُفَّارُكُمْ خَيْرٌ مِّنْ أُولَٰئِكُمْ أَمْ لَكُم بَرَاءَةٌ فِي الزُّبُرِ(43) Se awon alaigbagbo (ninu) yin l’o loore julo si awon wonyen (ti won ti pare bo seyin) ni tabi eyin ni imoribo kan ninu ipin-ipin Tira (pe eyin ko nii jiya) |
Tabi won n wi pe: "Gbogbo wa ni a oo ranra wa lowo lati bori (Ojise) |
A maa fo akojo naa logun. Won si maa fese fee loju ogun |
بَلِ السَّاعَةُ مَوْعِدُهُمْ وَالسَّاعَةُ أَدْهَىٰ وَأَمَرُّ(46) Amo sa, Akoko naa ni ojo adehun won. Akoko naa buru julo. O si koro julo |
Dajudaju awon elese wa ninu isina (nile aye, won yo si wa ninu) Ina jijo (ni orun) |
يَوْمَ يُسْحَبُونَ فِي النَّارِ عَلَىٰ وُجُوهِهِمْ ذُوقُوا مَسَّ سَقَرَ(48) Ni ojo ti A oo doju won dele wo inu Ina, (A o si so pe): E to ifowoba Ina wo |
Dajudaju A seda gbogbo nnkan pelu kadara |
Ase Wa (fun mimu nnkan be) ko tayo (ase) eyo kan soso gege bi iseju |
وَلَقَدْ أَهْلَكْنَا أَشْيَاعَكُمْ فَهَلْ مِن مُّدَّكِرٍ(51) Ati pe dajudaju A ti pa awon iru yin re. Nje oluranti wa bayii bi |
Gbogbo nnkan ti won se nise si wa ninu ipin-ipin tira |
Ati pe gbogbo nnkan kekere ati nnkan nla (ti won se) wa ni akosile |
Dajudaju awon oluberu (Allahu) yoo wa ninu awon Ogba (Idera) pelu awon odo (t’o n san ni isale re) |
Ni ibujokoo ododo nitosi Oba Alagbara Olukapa |
المزيد من السور باللغة اليوربا:
تحميل سورة القمر بصوت أشهر القراء :
قم باختيار القارئ للاستماع و تحميل سورة القمر كاملة بجودة عالية
أحمد العجمي
خالد الجليل
سعد الغامدي
سعود الشريم
عبد الباسط
عبد الله الجهني
علي الحذيفي
فارس عباد
ماهر المعيقلي
محمد جبريل
المنشاوي
الحصري
مشاري العفاسي
ناصر القطامي
ياسر الدوسري
Sunday, January 5, 2025
لا تنسنا من دعوة صالحة بظهر الغيب