Перевод суры Аль-Фаджр на Йоруба язык
وَالْفَجْرِ(1) Allahu bura pelu afemojumo |
O tun bura pelu awon oru mewaa kan |
O tun bura pelu meji ati eyo |
O tun bura pelu oru nigba ti o ba lo (ti o ba de) |
Nje ibura wa ninu iyen fun onilaakaye |
Se o o ri bi Oluwa re ti se oro ara ‘Ad |
(iyen awon iran) ’Irom, awon omiran |
awon ti A o da iru won mo sinu ilu |
Ati awon Thamud ti won gbe (ile igbe) sinu apata ninu afonifoji |
ati Fir‘aon eleekan (iya) |
(Awon wonyi ni) awon t’o tayo enu-ala ninu ilu |
Won si se ibaje pupo sinu re |
Oluwa re si rojo iya le won lori |
Dajudaju Oluwa re wa ni ibuso (ise eda) |
Nitori naa, ni ti eniyan, nigba ti Oluwa re ba dan an wo, ti O pon on le, ti O si se idera fun un, nigba naa o maa wi pe: "Oluwa mi ti pon mi le |
وَأَمَّا إِذَا مَا ابْتَلَاهُ فَقَدَرَ عَلَيْهِ رِزْقَهُ فَيَقُولُ رَبِّي أَهَانَنِ(16) Sugbon nigba ti O ba dan an wo, ti O gan arisiki re le e lowo, nigba naa o maa wi pe: "Oluwa mi ti yepere mi |
Rara, ko ri bee. Amo, eyin ko saponle omo-orukan |
Ati pe eyin ko gbera yin longbe lati fun mekunnu ni ounje |
E tun n je ogun ni ijekuje |
Ati pe e nifee si dukia ni ife pupo |
Rara, (ko ye ko ri bee). Nigba ti won ba mi ile titi ni mimi titi (t’o run womuwomu, ti ko si koto, ti ko si gelemo) |
(ti) Oluwa re de pelu awon molaika ni owoowo owoowo |
وَجِيءَ يَوْمَئِذٍ بِجَهَنَّمَ ۚ يَوْمَئِذٍ يَتَذَكَّرُ الْإِنسَانُ وَأَنَّىٰ لَهُ الذِّكْرَىٰ(23) ni ojo yen ni won maa mu ina Jahanamo wa. Ni ojo yen, eniyan yoo ranti (oro ara re). Bawo si ni iranti naa se le wulo fun un |
O maa wi pe: "Yee, emi iba ti ti (ise rere) siwaju fun isemi mi |
Ni ojo yen, eni kan ko le fi iya je (eda) bi iru iya (ti) Allahu (yoo fi je e) |
Eni kan ko si le de (eda) ni igbekun bi iru igbekun (ti) Allahu (yoo fi de e) |
Iwo emi olufokanbale |
pada si odo Oluwa re ni oluyonu, eni iyonu |
Nitori naa, wole saaarin awon erusin Mi |
Wo inu Ogba Idera Mi |
Больше сур в Йоруба:
Скачать суру Al-Fajr с голосом самых известных рекитаторов Корана:
Сура Al-Fajr mp3: выберите рекитатора, чтобы прослушать и скачать главу Al-Fajr полностью в высоком качестве
Ahmed Al Ajmy
Bandar Balila
Khalid Al Jalil
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdul Rashid Sufi
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Yasser Al Dosari
Помолитесь за нас хорошей молитвой