سوره ق به زبان یوروبا
Ƙof. (Allahu fi) al-Ƙur’an alapon-onle bura |
بَلْ عَجِبُوا أَن جَاءَهُم مُّنذِرٌ مِّنْهُمْ فَقَالَ الْكَافِرُونَ هَٰذَا شَيْءٌ عَجِيبٌ(2) Sugbon won seemo nitori pe olukilo kan wa ba won lati aarin ara won. Awon alaigbagbo si wi pe: "Eyi ni ohun iyanu |
أَإِذَا مِتْنَا وَكُنَّا تُرَابًا ۖ ذَٰلِكَ رَجْعٌ بَعِيدٌ(3) Se nigba ti a ba ti ku, ti a ti di erupe (ni a oo tun ji dide pada). Iyen ni idapada to jinna (si nnkan ti o le sele) |
قَدْ عَلِمْنَا مَا تَنقُصُ الْأَرْضُ مِنْهُمْ ۖ وَعِندَنَا كِتَابٌ حَفِيظٌ(4) Dajudaju A ti mo ohun ti ile n mu je ninu won. Tira (ise eda ) ti won n so si wa ni odo Wa |
بَلْ كَذَّبُوا بِالْحَقِّ لَمَّا جَاءَهُمْ فَهُمْ فِي أَمْرٍ مَّرِيجٍ(5) Sibesibe won pe ododo (al-Ƙur’an) ni iro nigba ti o de ba won. Nitori naa, won ti wa ninu idaamu |
Se won ko wo sanmo oke won bi A ti se mo on pa ati (bi) A ti se e ni oso, ti ko si si alafo sisan kan lara re |
وَالْأَرْضَ مَدَدْنَاهَا وَأَلْقَيْنَا فِيهَا رَوَاسِيَ وَأَنبَتْنَا فِيهَا مِن كُلِّ زَوْجٍ بَهِيجٍ(7) Ati pe ile, A te e perese. A si ju awon apata t’o duro gbagidi sinu re. A si mu orisirisi irugbin t’o dara hu jade lati inu re |
(O je) ariwoye ati iranti fun gbogbo erusin to n seri pada (sibi ododo) |
وَنَزَّلْنَا مِنَ السَّمَاءِ مَاءً مُّبَارَكًا فَأَنبَتْنَا بِهِ جَنَّاتٍ وَحَبَّ الْحَصِيدِ(9) A n so omi ibukun kale lati sanmo. A si n fi mu awon ogba oko ati awon eso ti won maa kaje hu jade |
(A tun mu) igi dabinu hu ga, ti awon eso ori re so jigbinni |
رِّزْقًا لِّلْعِبَادِ ۖ وَأَحْيَيْنَا بِهِ بَلْدَةً مَّيْتًا ۚ كَذَٰلِكَ الْخُرُوجُ(11) Arisiki ni fun awon eru (Allahu). A si n fi so oku ile di aye. Bayen ni ijade eda (lati inu saree yo se ri) |
كَذَّبَتْ قَبْلَهُمْ قَوْمُ نُوحٍ وَأَصْحَابُ الرَّسِّ وَثَمُودُ(12) Awon eniyan (Anabi) Nuh, awon eniyan Rass ati awon (eniyan) Thamud pe ododo niro siwaju won |
Ati awon ‘Ad, Fir‘aon ati awon omo iya (Anabi) Lut |
وَأَصْحَابُ الْأَيْكَةِ وَقَوْمُ تُبَّعٍ ۚ كُلٌّ كَذَّبَ الرُّسُلَ فَحَقَّ وَعِيدِ(14) ati awon ara ’Aekah ati awon ijo Tubba‘u; gbogbo won pe awon Ojise ni opuro. Nitori naa, ileri Mi si di eto (lori won) |
أَفَعَيِينَا بِالْخَلْقِ الْأَوَّلِ ۚ بَلْ هُمْ فِي لَبْسٍ مِّنْ خَلْقٍ جَدِيدٍ(15) Nje iseda akoko ko agara ba Wa bi? Rara, won wa ninu iyemeji nipa iseda (won) ni titun ni |
Dajudaju A seda eniyan. A si mo ohun ti emi re n so fun un. Awa si sunmo on ju isan orun re |
إِذْ يَتَلَقَّى الْمُتَلَقِّيَانِ عَنِ الْيَمِينِ وَعَنِ الشِّمَالِ قَعِيدٌ(17) (Ranti) nigba ti (molaika) awon agboro-sile meji ba beresi gba oro (sile), ti okan jokoo si otun, ti okan jokoo si osi |
مَّا يَلْفِظُ مِن قَوْلٍ إِلَّا لَدَيْهِ رَقِيبٌ عَتِيدٌ(18) (Eni kan) ko si nii so oro kan ayafi ki eso kan wa pelu re (fun akosile re) |
وَجَاءَتْ سَكْرَةُ الْمَوْتِ بِالْحَقِّ ۖ ذَٰلِكَ مَا كُنتَ مِنْهُ تَحِيدُ(19) Ati pe ipokaka iku yoo de lati fi ododo orun rinle. Iyen ni ohun ti iwo n sa fun |
Won a fon fere oniwo fun ajinde. Iyen ni ojo ileri naa |
Emi kookan yoo wa pelu oludari kan ati elerii kan (ninu awon molaika) |
لَّقَدْ كُنتَ فِي غَفْلَةٍ مِّنْ هَٰذَا فَكَشَفْنَا عَنكَ غِطَاءَكَ فَبَصَرُكَ الْيَوْمَ حَدِيدٌ(22) Dajudaju iwo ti wa ninu igbagbera nibi eyi. A si ti si ebibo (oju) re kuro fun o bayii. Nitori naa, iriran re yoo riran kedere ni oni |
(Molaika) alabaarin re yoo so pe: "Eyi ni ohun ti n be ni odo mi (gege bi akosile ise re) |
E ju u sinu ina Jahanamo, gbogbo alaigbagbo olorikunkun |
oludena-ise rere, alakoyo, oniyemeji |
الَّذِي جَعَلَ مَعَ اللَّهِ إِلَٰهًا آخَرَ فَأَلْقِيَاهُ فِي الْعَذَابِ الشَّدِيدِ(26) eni to mu olohun miiran mo Allahu. E ju u sinu iya lile |
۞ قَالَ قَرِينُهُ رَبَّنَا مَا أَطْغَيْتُهُ وَلَٰكِن كَانَ فِي ضَلَالٍ بَعِيدٍ(27) (Esu) alabaarin re yoo wi pe: "Oluwa wa, emi ko ni mo si i lona, sugbon o ti wa ninu isina to jinna (si ododo) teletele |
قَالَ لَا تَخْتَصِمُوا لَدَيَّ وَقَدْ قَدَّمْتُ إِلَيْكُم بِالْوَعِيدِ(28) (Allahu) yoo so pe: "E ma se sariyanjiyan lodo Mi. Mo kuku ti se ileri fun yin siwaju |
مَا يُبَدَّلُ الْقَوْلُ لَدَيَّ وَمَا أَنَا بِظَلَّامٍ لِّلْعَبِيدِ(29) Won ko si le yi oro naa pada ni odo Mi. Emi ko si nii se abosi si awon eru Mi |
يَوْمَ نَقُولُ لِجَهَنَّمَ هَلِ امْتَلَأْتِ وَتَقُولُ هَلْ مِن مَّزِيدٍ(30) (Ranti) ojo ti A oo so fun ina Jahnamo pe: Sebi o ti kun?" O si maa so pe: "Sebi afikun tun wa |
Won maa sun Ogba Idera mo awon oluberu (Allahu). Ko si nii jinna (si won) |
Eyi ni ohun ti A n se ni adehun fun gbogbo oluronupiwada, oluso (ofin Allahu) |
مَّنْ خَشِيَ الرَّحْمَٰنَ بِالْغَيْبِ وَجَاءَ بِقَلْبٍ مُّنِيبٍ(33) Enikeni ti o ba paya Allahu ni ikoko, ti o tun de pelu okan to seri pada si odo Allahu (nipa ironupiwada) |
(A oo so fun won pe:) "E wo inu (Ogba Idera) pelu alaafia. Iyen ni ojo gbere |
Ohun ti won n fe wa ninu re. Alekun si tun wa ni odo Wa |
Meloo meloo ninu awon ijo ti A ti pare siwaju won. Won si ni agbara ju won lo. (Nigba ti iya de) won sa asala kiri ninu ilu. Nje ibusasi kan wa (fun won bi) |
إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَذِكْرَىٰ لِمَن كَانَ لَهُ قَلْبٌ أَوْ أَلْقَى السَّمْعَ وَهُوَ شَهِيدٌ(37) Dajudaju iranti wa ninu iyen fun eni to ni okan tabi eni to fi eti sile, to wa nibe (pelu okan re) |
Dajudaju A seda awon sanmo, ile ati nnkan to wa laaarin awon mejeeji fun ojo mefa. Ko si re Wa rara (ambosibosi pe A oo sinmi ni ojo keje) |
Nitori naa, se suuru lori ohun ti won n wi. Ki o si se afomo pelu idupe fun Oluwa Re siwaju yiyo oorun ati wiwo (re) |
Ati pe ni oru ati ni eyin irun se afomo fun Un |
وَاسْتَمِعْ يَوْمَ يُنَادِ الْمُنَادِ مِن مَّكَانٍ قَرِيبٍ(41) Ki o si teti si ojo ti olupepe yoo pepe lati aye kan t’o sunmo |
يَوْمَ يَسْمَعُونَ الصَّيْحَةَ بِالْحَقِّ ۚ ذَٰلِكَ يَوْمُ الْخُرُوجِ(42) Ojo ti won yoo gbo igbe pelu ododo. Iyen ni ojo ijade eda (lati inu saree) |
Dajudaju Awa, Awa l’A n so eda di alaaye. A si n so o di oku. Odo Wa si ni abo eda |
يَوْمَ تَشَقَّقُ الْأَرْضُ عَنْهُمْ سِرَاعًا ۚ ذَٰلِكَ حَشْرٌ عَلَيْنَا يَسِيرٌ(44) (Ranti) ojo ti ile yoo faya perepere mo won lara, (ti won yoo maa) yara (jade lati inu ile). Iyen ni akojo t’o rorun fun Wa |
Awa nimo julo nipa ohun ti won n wi. Iwo ko si nii je won nipa (lati gbagbo). Nitori naa, fi al-Ƙur’an se iranti fun eni ti n paya ileri Mi |
سورهای بیشتر به زبان یوروبا:
دانلود سوره ق با صدای معروفترین قراء:
انتخاب خواننده برای گوش دادن و دانلود کامل سوره ق با کیفیت بالا.
أحمد العجمي
ابراهيم الاخضر
بندر بليلة
خالد الجليل
حاتم فريد الواعر
خليفة الطنيجي
سعد الغامدي
سعود الشريم
الشاطري
صلاح بوخاطر
عبد الباسط
عبدالرحمن العوسي
عبد الرشيد صوفي
عبدالعزيز الزهراني
عبد الله بصفر
عبد الله الجهني
علي الحذيفي
علي جابر
غسان الشوربجي
فارس عباد
ماهر المعيقلي
محمد أيوب
محمد المحيسني
محمد جبريل
المنشاوي
الحصري
مشاري العفاسي
ناصر القطامي
وديع اليمني
ياسر الدوسري
به قرآن کریم چنگ بزنید