La sourate Quraysh en Yoruba
(Ike ni lati odo Allahu) fun idile Ƙuraes lati wa papo ninu aabo |
(Ike ni se lati odo Allahu) fun won lati wa papo ninu aabo lori irin-ajo ni igba otutu ati igba ooru |
Nitori naa, ki won josin fun Oluwa Ile (Ka‘bah) yii |
Eni ti O fun won ni jije (ni asiko) ebi. O si fi won lokan bale ninu ipaya |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Quraysh : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Quraysh complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide