La sourate Al-Burooj en Yoruba
(Allahu) bura pelu sanmo ti awon ibuso (oorun, osupa ati awon irawo) wa ninu re |
O tun bura pelu ojo ti won se ni adehun |
O tun bura pelu olujerii ati ohun t’o jerii si |
A sebi le awon t’o gbe koto (ina) |
(iyen) ina ti won n fi igi ko (ninu koto) |
(Ranti) nigba ti won jokoo si itosi re |
Won si n wo ohun ti won n se fun awon onigbagbo ododo |
وَمَا نَقَمُوا مِنْهُمْ إِلَّا أَن يُؤْمِنُوا بِاللَّهِ الْعَزِيزِ الْحَمِيدِ(8) Ko si si kini kan ti won tori re je won niya bi ko se pe won ni igbagbo ododo ninu Allahu, Alagbara, Olope |
الَّذِي لَهُ مُلْكُ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ ۚ وَاللَّهُ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ شَهِيدٌ(9) Eni ti O ni ijoba awon sanmo ati ile. Allahu si ni Elerii lori gbogbo nnkan |
Dajudaju awon t’o fi inira kan awon onigbagbo ododo lokunrin ati awon onigbagbo ododo lobinrin, leyin naa ti won ko ronu piwada, iya ina Jahanamo n be fun won. Iya ina t’o n jo si wa fun won |
Dajudaju awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere, tiwon ni awon Ogba Idera kan, ti awon odo n san ni isale re. Iyen si ni erenje nla |
Dajudaju igbamu ti Oluwa re ma le |
Dajudaju Oun ni O pile (eda), O si maa da (eda) pada (fun ajinde) |
Oun ni Alaforijin, Ololufe (eda) |
Oun l’O ni Ite-ola, Eni-owo julo |
Oluse-ohun-t’O-ba-fe |
Sebi iro awon omo ogun ti de odo re |
(omo ogun) Fir‘aon ati (ijo) Thamud |
Sibesibe awon t’o sai gbagbo si n pe ododo niro |
Allahu si yi won ka leyin won |
Amo sa, ohun (ti A fi ranse si o ni) al-Ƙur’an alapon-onle |
ti o wa ninu walaa ti A n so |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Burooj : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Burooj complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide