Müzzemmil suresi çevirisi Yoruba
Iwo oludasobora |
Dide (kirun) ni oru ayafi fun igba die |
Lo ilaji re tabi din die ku ninu re |
Tabi fi kun un. Ki o si ke al-Ƙur’an ni pelepele |
Dajudaju Awa maa gbe oro t’o lagbara fun o |
إِنَّ نَاشِئَةَ اللَّيْلِ هِيَ أَشَدُّ وَطْئًا وَأَقْوَمُ قِيلًا(6) Dajudaju idide kirun loru, o wonu okan julo, o si dara julo fun kike (al-Ƙur’an) |
Dajudaju ise pupo wa fun o ni osan |
Ranti oruko Oluwa re. Ki o si da okan ko O patapata |
رَّبُّ الْمَشْرِقِ وَالْمَغْرِبِ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ فَاتَّخِذْهُ وَكِيلًا(9) Oluwa ibuyo oorun ati ibuwo oorun, ko si olohun ti ijosin to si afi Oun. Nitori naa, mu Un ni Alafeyinti |
وَاصْبِرْ عَلَىٰ مَا يَقُولُونَ وَاهْجُرْهُمْ هَجْرًا جَمِيلًا(10) Ki o si se suuru lori ohun ti won n wi. Pa won ti ni ipati t’o rewa |
وَذَرْنِي وَالْمُكَذِّبِينَ أُولِي النَّعْمَةِ وَمَهِّلْهُمْ قَلِيلًا(11) Fi Mi da awon olupe-ododo-niro, awon oloro. Ki o si lora fun won fun igba die |
Dajudaju sekeseke ati Ina Jehim n be lodo Wa |
Ounje hafunhafun ati iya eleta-elero (tun wa fun won) |
يَوْمَ تَرْجُفُ الْأَرْضُ وَالْجِبَالُ وَكَانَتِ الْجِبَالُ كَثِيبًا مَّهِيلًا(14) Ni ojo ti ile ati awon apata yoo maa mi titi pelu ohun igbe lile. Awon apata si maa di yanrin ti won kojo ti won tuka |
Dajudaju Awa ran Ojise kan nise si yin (ti o je) olujerii lori yin gege bi A se ran Ojise kan nise si Fir‘aon |
فَعَصَىٰ فِرْعَوْنُ الرَّسُولَ فَأَخَذْنَاهُ أَخْذًا وَبِيلًا(16) Sugbon Fir‘aon yapa Ojise naa. A si gba a mu ni igbamu lile |
فَكَيْفَ تَتَّقُونَ إِن كَفَرْتُمْ يَوْمًا يَجْعَلُ الْوِلْدَانَ شِيبًا(17) Ti eyin ba sai gbagbo, bawo ni eyin yoo se beru ojo kan t’o maa mu awon omode hewu |
Sanmo si maa faya perepere ninu re. Adehun Re je ohun ti o maa se |
إِنَّ هَٰذِهِ تَذْكِرَةٌ ۖ فَمَن شَاءَ اتَّخَذَ إِلَىٰ رَبِّهِ سَبِيلًا(19) Dajudaju eyi ni iranti. Nitori naa, eni ti o ba fe ki o mu oju ona kan to de odo Oluwa re |
Dajudaju Oluwa re mo pe dajudaju iwo n dide kirun fun ohun t’o kere si ilata meji oru tabi ilaji re tabi ilata re. Igun kan ninu awon t’o wa pelu re (naa n se bee). Allahu l’O n sodiwon oru ati osan. O si mo pe e ko le so o. Nitori naa, O ti da a pada si fifuye fun yin. Nitori naa, e ke ohun ti o ba rorun (fun yin) ninu al-Ƙur’an. O mo pe awon alaisan yoo wa ninu yin. Awon miiran si n ririn ajo lori-ile, ti won n wa ninu oore Allahu. Awon miiran si n jagun fun esin Allahu. Nitori naa, e ke ohun ti o ba rorun (fun yin) ninu re. E kirun (oran-an-yan). E yo Zakah. Ki e si ya Allahu ni dukia t’o dara. Ohunkohun ti e ba ti siwaju fun emi ara yin ninu ohun rere, eyin yoo ba a lodo Allahu ni ohun rere ati ni ohun ti o tobi julo ni esan. E toro aforijin lodo Allahu. Dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun |
Yoruba diğer sureler:
En ünlü okuyucuların sesiyle Müzzemmil Suresi indirin:
Surah Al-Muzzammil mp3: yüksek kalitede dinlemek ve indirmek için okuyucuyu seçerek
Ahmed El Agamy
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Ali Al Hudhaifi
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Muhammad Jibril
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Nasser Al Qatami
Yasser Al Dosari
Bizim için dua et, teşekkürler