Tin suresi çevirisi Yoruba
Allahu bura pelu eso tin ati eso zaetun |
O tun bura pelu apata Sinin |
O tun bura pelu ilu ifayabale yii |
Dajudaju A seda eniyan pelu irisi t’o dara julo |
Leyin naa, A maa da a pada si isale patapata (ninu Ina) |
إِلَّا الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ فَلَهُمْ أَجْرٌ غَيْرُ مَمْنُونٍ(6) Ayafi awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere. Nitori naa, esan ti ko nii pin (ti ko nii pedin) n be fun won |
Ta l’o tun n pe o ni opuro nipa Ojo esan leyin (oro yii) |
Se Allahu ko ni Eni t’O mo ejo da julo ninu awon adajo ni |
Yoruba diğer sureler:
En ünlü okuyucuların sesiyle Tin Suresi indirin:
Surah At-Tin mp3: yüksek kalitede dinlemek ve indirmek için okuyucuyu seçerek
Ahmed El Agamy
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Ali Al Hudhaifi
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Muhammad Jibril
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Nasser Al Qatami
Yasser Al Dosari
Bizim için dua et, teşekkürler