La sourate Al-Maun en Yoruba
So fun mi nipa eni t’o n pe Ojo Esan niro |
Iyen ni eni t’o n le omo-orukan danu |
Ko si nii gbiyanju lati bo mekunnu |
Egbe ni fun awon (munaafiki) t’o n kirun; ko tumo si “ohun t’o n run eniyan”. Amo itumo “irun” ni “ohun t’o n run ese olukirun” nitori pe ti olukirun ba ti se aluwala ni o ti san gbogbo awon ese weere ti o ti fi awon orikee ara re se siwaju. Bakan naa |
awon t’o n gbagbe lati kirun won ni asiko re |
awon t’o n se sekarimi |
ati pe won n hanna ohun elo (fun awon eniyan) |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Maun : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Maun complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide