La sourate As-Saff en Yoruba
سَبَّحَ لِلَّهِ مَا فِي السَّمَاوَاتِ وَمَا فِي الْأَرْضِ ۖ وَهُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ(1) Ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ohunkohun t’o wa ninu ile n safomo fun Allahu. Oun si ni Alagbara, Ologbon |
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا لِمَ تَقُولُونَ مَا لَا تَفْعَلُونَ(2) Eyin ti e gbagbo ni ododo, nitori ki ni e se n so ohun ti e o nii se nise |
كَبُرَ مَقْتًا عِندَ اللَّهِ أَن تَقُولُوا مَا لَا تَفْعَلُونَ(3) O je ohun ibinu t’o tobi ni odo Allahu pe ki e so ohun ti e o nii se |
إِنَّ اللَّهَ يُحِبُّ الَّذِينَ يُقَاتِلُونَ فِي سَبِيلِهِ صَفًّا كَأَنَّهُم بُنْيَانٌ مَّرْصُوصٌ(4) Dajudaju Allahu feran awon t’o n jagun fun esin Re (ti won to ni) owoowo bi eni pe ogiri ile ti won le po mora won ni won |
(Ranti) nigba ti (Anabi) Musa so fun ijo re pe: "Eyin ijo mi, nitori ki ni e oo se fi inira kan mi. E si kuku mo pe dajudaju Ojise Allahu ni emi je si yin." Nigba ti won si ye (kuro nibi ododo), Allahu ye okan won. Allahu ko si nii fi ona mo ijo obileje |
(Ranti) nigba ti ‘Isa omo Moryam so pe: "Eyin omo ’Isro’il, dajudaju emi ni Ojise Allahu si yin. Mo n fi ohun t’o je ododo rinle nipa eyi t’o siwaju mi ninu Taorah. Mo si n mu iro-idunnu wa nipa Ojise kan t’o n bo leyin mi. Oruko re ni ’Ahmod." Nigba ti o ba si wa ba won pelu awon eri t’o yanju, won a wi pe: "Idan ponnbele ni eyi |
Ta si ni o sabosi t’o tayo eni ti o da adapa iro mo Allahu, ti won si n pe e sinu ’Islam! Allahu ko si nii fi ona mo ijo alabosi |
Won n gbero lati fi (oro) enu won pa imole Allahu. Allahu yo si mu imole Re tan kari, awon alaigbagbo ibaa korira re |
(Allahu) Oun ni Eni ti O fi imona ati esin ododo (’Islam) ran Ojise Re nitori ki O le fi bori esin (miiran), gbogbo re patapata, awon osebo ibaa korira re |
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا هَلْ أَدُلُّكُمْ عَلَىٰ تِجَارَةٍ تُنجِيكُم مِّنْ عَذَابٍ أَلِيمٍ(10) Eyin ti e gbagbo ni ododo, se ki Ng toka yin si okowo kan ti o maa gba yin la ninu iya eleta-elero |
E gbagbo ninu Allahu ati Ojise Re, e jagun soju ona (esin) Allahu pelu awon dukia yin ati emi yin. Iyen loore julo fun yin ti e ba mo |
(Allahu) maa fori ese yin jin yin. O si maa mu yin wo inu awon Ogba Idera, ti awon odo n san ni isale re ati awon ibugbe t’o dara ninu awon Ogba Idera gbere. Iyen ni erenje nla |
وَأُخْرَىٰ تُحِبُّونَهَا ۖ نَصْرٌ مِّنَ اللَّهِ وَفَتْحٌ قَرِيبٌ ۗ وَبَشِّرِ الْمُؤْمِنِينَ(13) Ati nnkan miiran ti e tun nifee si; (iyen,) aranse lati odo Allahu ati isegun t’o sunmo. Ki o si fun awon onigbagbo ododo ni iro idunnu |
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e je alaranse fun esin Allahu gege bi (Anabi) ‘Isa omo Moryam se so fun awon omoleyin re pe: "Ta ni o maa se iranlowo fun mi nipa esin Allahu?" Awon omoleyin re so pe: "Awa ni alaranse fun esin Allahu." Igun kan ninu awon omo ’Isro’il gba a gbo ni ododo nigba naa, igun kan si sai gbagbo ninu re. A si fun awon t’o gbagbo lagbara lori awon ota won; won si di olubori |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate As-Saff : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate As-Saff complète en haute qualité.
![surah As-Saff Ahmed El Agamy mp3 surah As-Saff Ahmed El Agamy](https://i.pinimg.com/564x/b1/9f/03/b19f03a9f2f09c46afbfd4f03727aee7.jpg)
![surah As-Saff Bandar Balila mp3 surah As-Saff Bandar Balila](https://i.pinimg.com/564x/3e/27/fa/3e27fa5bbbd4d19ee2f4b4975224913e.jpg)
![surah As-Saff Khalid Al Jalil mp3 surah As-Saff Khalid Al Jalil](https://i.pinimg.com/564x/9b/26/36/9b2636f5bbf7ef72abdb817018e96a4d.jpg)
![surah As-Saff Saad Al Ghamdi mp3 surah As-Saff Saad Al Ghamdi](https://i.pinimg.com/564x/85/27/cf/8527cf694f379425e43b9a4fe54b6cfb.jpg)
![surah As-Saff Saud Al Shuraim mp3 surah As-Saff Saud Al Shuraim](https://i.pinimg.com/564x/ad/79/67/ad79679d76062df7166c6e2f52d397d6.jpg)
![surah As-Saff Abdul Basit Abdul Samad mp3 surah As-Saff Abdul Basit Abdul Samad](https://i.pinimg.com/564x/52/95/ae/5295ae7c08e4ebdc7eda3ddb5c6c0a19.jpg)
![surah As-Saff Abdul Rashid Sufi mp3 surah As-Saff Abdul Rashid Sufi](https://i.pinimg.com/564x/80/56/ee/8056ee030160e5c7216811b7b209343c.jpg)
![surah As-Saff Abdullah Basfar mp3 surah As-Saff Abdullah Basfar](https://i.pinimg.com/236x/f5/7b/a1/f57ba14ba4844cee88cdf7cfb2b06510.jpg)
![surah As-Saff Abdullah Awwad Al Juhani mp3 surah As-Saff Abdullah Awwad Al Juhani](https://i.pinimg.com/564x/aa/4d/0b/aa4d0b16c5fbc41efcd692947a4d75ad.jpg)
![surah As-Saff Fares Abbad mp3 surah As-Saff Fares Abbad](https://s-media-cache-ak0.pinimg.com/564x/2b/28/ae/2b28aef3f9678b7cd89315d5ffceba2f.jpg)
![surah As-Saff Maher Al Muaiqly mp3 surah As-Saff Maher Al Muaiqly](https://s-media-cache-ak0.pinimg.com/564x/ab/cc/99/abcc9949d0419ef1f0963a54aef06397.jpg)
![surah As-Saff Al Minshawi mp3 surah As-Saff Muhammad Siddiq Al Minshawi](https://i.pinimg.com/564x/21/76/8d/21768d297bd3460f7339b7b755f53d03.jpg)
![surah As-Saff Mahmoud Khalil Al Hosary mp3 surah As-Saff Al Hosary](https://i.pinimg.com/564x/3f/da/7e/3fda7ed5056347e700cac64d07e164c3.jpg)
![surah As-Saff Mishari Al-afasi mp3 surah As-Saff Al-afasi](https://i.pinimg.com/564x/0a/40/9e/0a409ef09a55700877c20d7195fe9126.jpg)
![surah As-Saff Yasser Al Dosari mp3 surah As-Saff Yasser Al Dosari](https://s-media-cache-ak0.pinimg.com/564x/32/3e/17/323e173f4833680898f51240bedd4973.jpg)
Donnez-nous une invitation valide