La sourate Al-Inshiqaq en Yoruba
Nigba ti sanmo ba faya perepere |
o gbo, o si tele ase Oluwa re ni. O si di dandan fun un lati se bee – |
ati nigba ti A ba fe ile loju |
o maa ju ohun ti o wa ninu re sita, o si maa pa sofo |
– o gbo, o si tele ase Oluwa re ni. O si di dandan fun un lati se bee – (ni ojo yen ni eda maa ri ise owo re) |
يَا أَيُّهَا الْإِنسَانُ إِنَّكَ كَادِحٌ إِلَىٰ رَبِّكَ كَدْحًا فَمُلَاقِيهِ(6) Iwo eniyan dajudaju iwo n se ise karakara ni ise asepade Oluwa re. O si maa mu un pade Re |
Nitori naa, ni ti eni ti won ba fun ni iwe ise re ni owo otun re |
laipe A maa se isiro-ise (re) ni isiro irorun |
O si maa pada si odo awon eniyan re (ninu Ogba Idera) leni idunnu |
Ni ti eni ti won ba si fun ni iwe ise re lati eyin re |
laipe o maa kigbe iparun |
O si maa wo inu Ina t’o n jo fofo |
Dajudaju o ti wa laaarin awon eniyan re leni idunnu (si aigbagbo nile aye) |
Dajudaju o lero pe oun ko nii pada (si odo Allahu ni) |
Rara (o maa pada). Dajudaju Oluwa re je Oluriran nipa re |
Nitori naa, Emi (Allahu) n bura pelu awonpapa |
Mo tun bura pelu oru ati ohun ti o ko jo sinu re |
Mo tun bura pelu osupa nigba ti o ba degba (pelu imole re) |
Dajudaju eyin yoo maa bo sinu wahala kan lati inu wahala kan |
Ki l’o se won na ti won ko fi gbagbo ni ododo |
Nigba ti won ba si ke al-Ƙur’an fun won, won ko nii fori kanle |
Rara, nse ni awon t’o sai gbagbo n pe e niro |
Allahu si nimo julo nipa ohun ti won n fi pamo (sinu okan won) |
Nitori naa, fun won ni iro iya eleta-elero |
إِلَّا الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ لَهُمْ أَجْرٌ غَيْرُ مَمْنُونٍ(25) Ayafi awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere, esan ti ko nii pin n be fun won |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Inshiqaq : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Inshiqaq complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide