La sourate Al-Alaq en Yoruba
Ke (al-Ƙur’an) pelu oruko Oluwa re, Eni ti O da eda |
O seda eniyan lati ara eje didi |
Ke e. Oluwa re ni Alapon-onle julo |
Eni ti O fi imo nipa gege ikowe mo eniyan |
O fi imo ti eniyan ko mo mo on |
Ni ti ododo, dajudaju eniyan kuku n tayo enu-ala |
nitori pe o rira re ni oloro |
Dajudaju odo Oluwa re ni abo eda |
So fun mi nipa eni t’o n ko |
fun erusin kan nigba ti (erusin naa) kirun |
So fun mi (nipa esan re) ti o ba je pe o wa lori imona (’Islam) |
tabi pe o pase iberu (Allahu) |
So fun mi (nipa iya re) ti o ba je pe o pe ododo niro, ti o si keyin si i |
Se ko mo pe dajudaju Allahu n ri (oun ni) |
Bee ni (Allahu n ri i.) Dajudaju ti ko ba jawo (nibi didi i lowo), dajudaju A maa fi aaso ori re wo o (sinu Ina) |
aaso ori opuro, elese |
Nitori naa, ki o pe awon olubajokoo re |
Awa maa pe awon molaika eso Ina |
Rara o, ma se tele tire. Fori kanle (ki o kirun), ki o sunmo (Allahu) |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Alaq : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Alaq complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide