La sourate Az-Zalzalah en Yoruba
Nigba ti won ba mi ile titi ni imititi re |
ati (nigba) ti ile ba tu awon eru t’o wuwo ninu re jade |
eniyan yo si wi pe: "Ki l’o mu un |
Ni ojo yen ni (ile) yoo soro nipa awon iro re (ti eda gbe ori ile se) |
Nitori pe dajudaju Oluwa re l’O fun un ni ase (lati soro) |
يَوْمَئِذٍ يَصْدُرُ النَّاسُ أَشْتَاتًا لِّيُرَوْا أَعْمَالَهُمْ(6) Ni ojo yen, awon eniyan yoo maa gba ona otooto lo nitori ki won le fi awon ise won han won |
Nitori naa, eni ti o ba se ise rere ni odiwon omo ina-igun, o maa ri i |
Eni ti o ba si se ise aburu ni odiwon omo ina-igun, o maa ri i |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Az-Zalzalah : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Az-Zalzalah complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide