Tekasür suresi çevirisi Yoruba
Wiwa oore aye ni opolopo fun iyanran sise ti ko airoju fesin ba yin |
titi e fi wo inu saree |
Rara (ko ye ko ri bee, amo) laipe e maa mo |
Leyin naa, ni ododo laipe e maa mo |
Bee ni, ti o ba je pe e ni imo amodaju ni (eyin iba ti se bee) |
Dajudaju e maa ri ina Jehim |
Leyin naa, dajudaju e maa ri i ni aridaju |
Leyin naa, dajudaju ni ojo yen won maa bi yin leere nipa igbadun (aye yii) |
Yoruba diğer sureler:
En ünlü okuyucuların sesiyle Tekasür Suresi indirin:
Surah At-Takathur mp3: yüksek kalitede dinlemek ve indirmek için okuyucuyu seçerek
Ahmed El Agamy
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Ali Al Hudhaifi
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Muhammad Jibril
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Nasser Al Qatami
Yasser Al Dosari
Bizim için dua et, teşekkürler