İnsan suresi çevirisi Yoruba
هَلْ أَتَىٰ عَلَى الْإِنسَانِ حِينٌ مِّنَ الدَّهْرِ لَمْ يَكُن شَيْئًا مَّذْكُورًا(1) Sebi akoko kan ninu igba ti re koja lori eniyan ti (eniyan) ko je kini kan ti won n daruko |
إِنَّا خَلَقْنَا الْإِنسَانَ مِن نُّطْفَةٍ أَمْشَاجٍ نَّبْتَلِيهِ فَجَعَلْنَاهُ سَمِيعًا بَصِيرًا(2) Dajudaju Awa seda eniyan lati ara ato t’o ropo mora won (lati ara okunrin ati obinrin), ki A le dan an wo. A si se e ni olugbo, oluriran |
إِنَّا هَدَيْنَاهُ السَّبِيلَ إِمَّا شَاكِرًا وَإِمَّا كَفُورًا(3) Dajudaju A fi ona mo on; O le je oludupe, o si le je alaimoore |
إِنَّا أَعْتَدْنَا لِلْكَافِرِينَ سَلَاسِلَ وَأَغْلَالًا وَسَعِيرًا(4) Dajudaju Awa pese awon ewon, ajaga ati Ina sile de awon alaigbagbo |
إِنَّ الْأَبْرَارَ يَشْرَبُونَ مِن كَأْسٍ كَانَ مِزَاجُهَا كَافُورًا(5) Dajudaju awon eni rere, won yoo maa mu omi kan ninu ife. Ohun ti A popo mo (omi naa) ni kafura |
عَيْنًا يَشْرَبُ بِهَا عِبَادُ اللَّهِ يُفَجِّرُونَهَا تَفْجِيرًا(6) Omi iseleru kan ni, ti awon erusin Allahu yoo maa mu, ti won yo si maa mu un san jade daadaa (si ibi ti won ba fe) |
يُوفُونَ بِالنَّذْرِ وَيَخَافُونَ يَوْمًا كَانَ شَرُّهُ مُسْتَطِيرًا(7) Won n mu eje won se. Won si n paya ojo kan, ti aburu re je ohun ti o maa fonka gan-an |
وَيُطْعِمُونَ الطَّعَامَ عَلَىٰ حُبِّهِ مِسْكِينًا وَيَتِيمًا وَأَسِيرًا(8) Tohun ti bi won se ni ife si (oro to), won n fun mekunnu, omo orukan ati eru ni ounje je |
إِنَّمَا نُطْعِمُكُمْ لِوَجْهِ اللَّهِ لَا نُرِيدُ مِنكُمْ جَزَاءً وَلَا شُكُورًا(9) (Won si n so pe:) "Nitori Oju rere Allahu (nikan) l’a fi n fun yin ni ounje; awa ko si gbero esan tabi idupe kan lati odo yin |
إِنَّا نَخَافُ مِن رَّبِّنَا يَوْمًا عَبُوسًا قَمْطَرِيرًا(10) Dajudaju awa n paya ni odo Oluwa wa ojo kan ti (eda yoo) faju ro koko |
فَوَقَاهُمُ اللَّهُ شَرَّ ذَٰلِكَ الْيَوْمِ وَلَقَّاهُمْ نَضْرَةً وَسُرُورًا(11) Nitori naa, Allahu yoo so won nibi aburu ojo yen. O si maa fun won ni itutu oju ati idunnu |
O si maa san won ni esan Ogba Idera ati aso alari nitori pe won se suuru |
مُّتَّكِئِينَ فِيهَا عَلَى الْأَرَائِكِ ۖ لَا يَرَوْنَ فِيهَا شَمْسًا وَلَا زَمْهَرِيرًا(13) Won yoo maa rogbo ku sori awon ibusun won. Won ko si nii ri oorun tabi otutu |
وَدَانِيَةً عَلَيْهِمْ ظِلَالُهَا وَذُلِّلَتْ قُطُوفُهَا تَذْلِيلًا(14) Awon ooji (inu Ogba Idera) yoo sunmo won. A si maa mu awon eso ibe sunmo arowoto won ni ti sisunmo |
وَيُطَافُ عَلَيْهِم بِآنِيَةٍ مِّن فِضَّةٍ وَأَكْوَابٍ كَانَتْ قَوَارِيرَا(15) Ati pe won yoo maa gbe ife imumi nla ti won se lati ara fadaka ati awon ife imumi kekere ti o je alawo kaa kiri odo won |
Ife alawo ti won se lati ara fadaka ni (won). A si se won niwon-niwon (ti o se weku ohun ti won fe mu) |
وَيُسْقَوْنَ فِيهَا كَأْسًا كَانَ مِزَاجُهَا زَنجَبِيلًا(17) Ati pe won yoo maa fun won ni ife oti kan mu ninu (Ogba Idera). Ohun ti A popo mo (oti naa) ni atale |
Ninu Ogba Idera (won yoo tun maa mu) omi iseleru kan, ti A n pe ni omi salsabil |
۞ وَيَطُوفُ عَلَيْهِمْ وِلْدَانٌ مُّخَلَّدُونَ إِذَا رَأَيْتَهُمْ حَسِبْتَهُمْ لُؤْلُؤًا مَّنثُورًا(19) Awon odokunrin ti ko nii gbo yo si maa lo bo laaarin won. Nigba ti iwo ba si ri won, iwo yoo ka won kun okuta olowo iyebiye ti won tan kale |
وَإِذَا رَأَيْتَ ثَمَّ رَأَيْتَ نَعِيمًا وَمُلْكًا كَبِيرًا(20) Nigba ti iwo ba si wo ibe yen (ninu Ogba Idera), iwo yoo ri idera ati ola t’o tobi |
Aso ara won ni aso aran felefele alawo eweko ati aso alagbaaa. A si maa fi egba-owo onifadaka se won ni oso. Oluwa won yo si fun won ni ohun mimu mimo mu |
إِنَّ هَٰذَا كَانَ لَكُمْ جَزَاءً وَكَانَ سَعْيُكُم مَّشْكُورًا(22) Dajudaju eyi je esan fun yin. Ise yin si ja si ope |
Dajudaju Awa l’A so al-Ƙur’an kale fun o diedie |
فَاصْبِرْ لِحُكْمِ رَبِّكَ وَلَا تُطِعْ مِنْهُمْ آثِمًا أَوْ كَفُورًا(24) Nitori naa, se suuru fun idajo Oluwa re. Ma se tele elese tabi alaimoore kan ninu won |
Ranti oruko Oluwa re ni aaro ati ni asale |
وَمِنَ اللَّيْلِ فَاسْجُدْ لَهُ وَسَبِّحْهُ لَيْلًا طَوِيلًا(26) Ati ni oru, fori kanle fun Un. Ki o si safomo fun Un ni oru fun igba pipe |
إِنَّ هَٰؤُلَاءِ يُحِبُّونَ الْعَاجِلَةَ وَيَذَرُونَ وَرَاءَهُمْ يَوْمًا ثَقِيلًا(27) Dajudaju awon wonyi feran aye. Won si n pa ojo t’o wuwo ti seyin won |
نَّحْنُ خَلَقْنَاهُمْ وَشَدَدْنَا أَسْرَهُمْ ۖ وَإِذَا شِئْنَا بَدَّلْنَا أَمْثَالَهُمْ تَبْدِيلًا(28) Awa l’A seda won. A si se won ni alagbara. Nigba ti A ba si fe, A oo fi iru won (miiran) paaro won ni ti ipaaro |
إِنَّ هَٰذِهِ تَذْكِرَةٌ ۖ فَمَن شَاءَ اتَّخَذَ إِلَىٰ رَبِّهِ سَبِيلًا(29) Dajudaju eyi ni iranti. Nitori naa, eni ti o ba fe ki o mu oju ona to si odo Oluwa re |
وَمَا تَشَاءُونَ إِلَّا أَن يَشَاءَ اللَّهُ ۚ إِنَّ اللَّهَ كَانَ عَلِيمًا حَكِيمًا(30) Eyin ko si nii fe (kini kan) afi ti Allahu ba fe. Dajudaju Allahu n je Onimo, Ologbon |
يُدْخِلُ مَن يَشَاءُ فِي رَحْمَتِهِ ۚ وَالظَّالِمِينَ أَعَدَّ لَهُمْ عَذَابًا أَلِيمًا(31) O maa fi eni ti o ba fe sinu ike re. (Ni ti) awon alabosi, O si pese iya eleta-elero sile de won |
Yoruba diğer sureler:
En ünlü okuyucuların sesiyle İnsan Suresi indirin:
Surah Al-Insan mp3: yüksek kalitede dinlemek ve indirmek için okuyucuyu seçerek
Ahmed El Agamy
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Ali Al Hudhaifi
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Muhammad Jibril
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Nasser Al Qatami
Yasser Al Dosari
Bizim için dua et, teşekkürler