La sourate Al-Fatihah en Yoruba
| Ni oruko Allahu, Ajoke-aye, Asake-orun |
| Gbogbo ope n je ti Allahu, Oluwa gbogbo eda |
| Ajoke-aye, Asake-orun |
| Olukapa-ojo-esan |
| Iwo nikan ni a n josin fun. Odo Re nikan si ni a n wa oore si |
| Jijosin fun Allahu nikan soso ati diduro sinsin ninu ijosin Re itumo yii wa bee ninu surah Ali ‘Imron “Fi ese wa rinle sinu ’Islam ona taara.” Nitori naa |
صِرَاطَ الَّذِينَ أَنْعَمْتَ عَلَيْهِمْ غَيْرِ الْمَغْضُوبِ عَلَيْهِمْ وَلَا الضَّالِّينَ(7) ona awon ti O se idera fun,yato si (ona) awon eni-ibinu (iyen, awon yehudi) ati (ona) awon olusina (iyen, awon nasara) |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Fatihah : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Fatihah complète en haute qualité.
Ahmed Al Ajmy
Bandar Balila
Khalid Al Jalil
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdul Rashid Sufi
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Yasser Al Dosari
Donnez-nous une invitation valide




