La sourate Al-Qariah en Yoruba
الْقَارِعَةُ(1) Akoko ijaya |
Ki ni Akoko ijaya |
Ki si l’o mu o mo ohun t’o n je Akoko ijaya |
(Ohun ni) ojo ti eniyan yo da bi afopina ti won fonka sita |
awon apata yo si da bi owu ti won gbon danu |
Nitori naa, ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba te won |
o si maa wa ninu isemi t’o yonu si |
Ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba si fuye |
Hawiyah si ni ibugbe re |
Ki si o mu o mo ohun t’o n je bee |
نَارٌ حَامِيَةٌ(11) (Ohun ni) Ina gbigbona gan-an |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Qariah : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Qariah complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide