Fatiha suresi çevirisi Yoruba
Ni oruko Allahu, Ajoke-aye, Asake-orun |
Gbogbo ope n je ti Allahu, Oluwa gbogbo eda |
Ajoke-aye, Asake-orun |
Olukapa-ojo-esan |
Iwo nikan ni a n josin fun. Odo Re nikan si ni a n wa oore si |
Jijosin fun Allahu nikan soso ati diduro sinsin ninu ijosin Re itumo yii wa bee ninu surah Ali ‘Imron “Fi ese wa rinle sinu ’Islam ona taara.” Nitori naa |
صِرَاطَ الَّذِينَ أَنْعَمْتَ عَلَيْهِمْ غَيْرِ الْمَغْضُوبِ عَلَيْهِمْ وَلَا الضَّالِّينَ(7) ona awon ti O se idera fun,yato si (ona) awon eni-ibinu (iyen, awon yehudi) ati (ona) awon olusina (iyen, awon nasara) |
Yoruba diğer sureler:
En ünlü okuyucuların sesiyle Fatiha Suresi indirin:
Surah Al-Fatihah mp3: yüksek kalitede dinlemek ve indirmek için okuyucuyu seçerek
Ahmed El Agamy
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Ali Al Hudhaifi
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Muhammad Jibril
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Nasser Al Qatami
Yasser Al Dosari
Bizim için dua et, teşekkürler