La sourate Al-Humazah en Yoruba
| Egbe ni fun gbogbo abuniloju-eni, abunileyin-eni |
| eni ti o ko owo jo, ti o si ka a lakatunka (lai na an fesin) |
| O n lero pe dajudaju dukia re yoo mu un se gbere (nile aye) |
| Rara (ko ri bee). Dajudaju won maa ku u loko sinu Hutomoh ni |
| Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Hutomoh |
| (Ohun ni) Ina Allahu ti won n ko (t’o n jo geregere) |
| eyi ti o maa jo (eda) wo inu okan lo |
| Dajudaju won maa ti (awon ilekun) Ina pa mo won lori patapata |
| (Won maa wa) laaarin awon opo kiribiti giga (ninu Ina) |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Humazah : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Humazah complète en haute qualité.
Ahmed Al Ajmy
Bandar Balila
Khalid Al Jalil
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdul Rashid Sufi
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Yasser Al Dosari
Donnez-nous une invitation valide




