La sourate Al-Infitar en Yoruba
Nigba ti sanmo ba fa ya perepere |
ati nigba ti awon irawo ba ja bo kaakiri |
ati nigba ti awon ibudo ba san jara won |
ati (nigba ti A ba ta ile soke), ti A si mu awon oku jade (laaye) lati inu awon saree |
(nigba naa ni) emi kookan yoo mo ohun ti o ti siwaju (ninu ise re) ati ohun ti o fi seyin (ninu oripa ise re) |
يَا أَيُّهَا الْإِنسَانُ مَا غَرَّكَ بِرَبِّكَ الْكَرِيمِ(6) Iwo eniyan, ki ni o tan o je nipa Oluwa re, Alapon-onle |
Eni t’O seda re? O seda re ni pipe. O si mu o dogba jale leeyan |
O to eya ara re papo sinu eyikeyii aworan ti O fe |
Ni ti ododo, nse l’e n pe Ojo esan niro |
Dajudaju awon eso si wa ni odo yin |
(Won je) alapon-onle, onkowe-ise eda |
Won mo ohun ti e n se nise |
Dajudaju awon eni rere yoo kuku wa ninu igbadun |
Dajudaju awon eni ibi yo si kuku wa ninu ina Jehim |
Won yoo wo inu re ni Ojo esan |
Won ko si nii kuro ninu re |
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Ojo esan |
Leyin naa, ki ni o mu o mo ohun t’o n je Ojo esan |
يَوْمَ لَا تَمْلِكُ نَفْسٌ لِّنَفْسٍ شَيْئًا ۖ وَالْأَمْرُ يَوْمَئِذٍ لِّلَّهِ(19) (Ojo esan ni) ojo ti emi kan ko nii kapa kini kan fun emi kan. Gbogbo ase ojo yen si n je ti Allahu |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Infitar : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Infitar complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide