La sourate Ad-Dhuha en Yoruba
وَالضُّحَىٰ(1) (Allahu bura pelu) iyaleta |
| O tun bura pelu ale nigba ti (ile) ba su |
| Oluwa re ko pa o ti, ko si binu si o |
| Dajudaju orun loore fun o ju aye lo |
| Dajudaju laipe Oluwa re maa fun o ni (oore pupo ni orun). Nitori naa, o si maa yonu si i |
| Se (Allahu) ko ri o ni omo-orukan ni? O si fun o ni ibugbe |
| O si ri o ni alaimona (iyen siwaju isokale imisi). O si fi ona mo o |
| O tun ri o ni alaini, O si ro o loro |
| Nitori naa, ni ti omo-orukan, ma se je gaba (le e lori) |
| Ni ti alagbe, ma si se jagbe (mo on) |
| Ni ti idera Oluwa re, so o jade |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Ad-Dhuha : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Ad-Dhuha complète en haute qualité.
Ahmed Al Ajmy
Bandar Balila
Khalid Al Jalil
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdul Rashid Sufi
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Yasser Al Dosari
Donnez-nous une invitation valide




