La sourate Al-Adiyat en Yoruba
Allahu bura pelu awon esin t’o n sare t’o n mi helehele ni oju-ogun |
O tun bura pelu awon esin ti patako ese won n sana (nibi ere sisa) |
O tun bura pelu awon esin t’o n kolu ota esin ni owuro kutukutu |
Won si fi (patako ese won) tu eruku (ile ota) soke |
Won tun be gija papo pelu re saaarin akojo ota |
Dajudaju eniyan ni alaimoore si Oluwa re |
Dajudaju Allahu si n je Elerii lori iyen |
Ati pe dajudaju eniyan le gan-an nibi ife oore aye |
Se ko mo pe nigba ti won ba tu ohun t’o wa ninu saree jade (fun ajinde) |
ti won si tu ohun t’o wa ninu igba-aya eda sita patapata |
dajudaju Oluwa won ni Alamotan nipa won ni Ojo yen |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Adiyat : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Adiyat complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide