La sourate Ash-Sharh en Yoruba
Se A o sipaya igba-aya re fun o bi |
A si gbe ese re kuro lorun re |
eyi ti o wo o lorun. amo ti onitoun pada gba ’Islam ibaa je pe o gba a ni owuro |
A si gbe iranti oruko re ga fun o |
Nitori naa, dajudaju idekun wa leyin inira |
Dajudaju idekun wa leyin inira se |
Nitori naa, nigba ti o ba buse (lori okan), gbiyanju (omiran) |
Odo Oluwa re si ni ki o soju kokoro oore si |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Ash-Sharh : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Ash-Sharh complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide