سورة المعارج باليوربا
Onibeeere kan beere nipa iya t’o maa sele |
si awon alaigbagbo. Ko si si eni ti o maa di i lowo |
lodo Allahu, Onipo-aye giga |
تَعْرُجُ الْمَلَائِكَةُ وَالرُّوحُ إِلَيْهِ فِي يَوْمٍ كَانَ مِقْدَارُهُ خَمْسِينَ أَلْفَ سَنَةٍ(4) Awon molaika ati molaika Jibril n gunke wa si odo Re ninu ojo kan ti odiwon re je oke meji aabo (ti e ba fe rin in) |
Nitori naa, se suuru ni suuru t’o rewa |
Dajudaju won n wo (iya naa) ni ohun t’o jinna |
A si n wo o ni ohun t’o sunmo |
(Ojo naa ni) ojo ti sanmo yo da bi ide t’o yo |
awon apata yo si da bi egbon owu-irun |
ore imule kan ko si nii beere ore imule (re) |
يُبَصَّرُونَهُمْ ۚ يَوَدُّ الْمُجْرِمُ لَوْ يَفْتَدِي مِنْ عَذَابِ يَوْمِئِذٍ بِبَنِيهِ(11) Won maa ri ara won (won si maa dara won mo). Elese si maa fe ki oun fi awon omo re serapada emi ara re nibi Iya ni ojo yen |
Iyawo re ati arakunrin re |
ati awon ebi re t’o pa ti, ti awon si n gba a sodo nile aye |
ati gbogbo eni t’o wa lori ile aye patapata, (o maa fe fi won serapada emi ara re nibi Iya). Leyin naa, (o maa fe) ki Allahu gba oun la (ninu iya Ina) |
Rara! Dajudaju (o maa wo) ina Latho (ina t’o n jo fofo) |
O maa bo awo ori toro |
(Ina) yo maa ke si eni t’o keyin si (igbagbo ododo), ti o si takete si i |
o ko (oro) jo, o si fi pamo (ko na an fun esin) |
Dajudaju eniyan, A seda re ni alailokan, okanjua |
Nigba ti aburu ba fowo ba a, o maa kanra gogo |
Nigba ti owo re ba si te oore, o maa yahun |
Ayafi awon olukirun |
awon oludunnimo irun won |
awon t’o mo ojuse (won) ninu dukia won |
si alagbe ati eni ti A se arisiki ni eewo fun |
awon t’o n gba ojo esan gbo ni ododo |
awon t’o n paya iya Oluwa won |
dajudaju iya Oluwa won ko see fayabale si |
awon t’o n so abe won |
إِلَّا عَلَىٰ أَزْوَاجِهِمْ أَوْ مَا مَلَكَتْ أَيْمَانُهُمْ فَإِنَّهُمْ غَيْرُ مَلُومِينَ(30) ayafi lodo awon iyawo won tabi erubinrin won ni won ko ti le je eni-eebu |
فَمَنِ ابْتَغَىٰ وَرَاءَ ذَٰلِكَ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الْعَادُونَ(31) nitori naa, eni keni t’o ba n wa nnkan miiran leyin iyen, awon wonyen ni awon olutayo-enu ala |
awon t’o n so agbafipamo won ati adehun won |
awon t’o n duro ti ijerii won |
ati awon t’o n so awon irun won |
Awon wonyen ni alapon-onle ninu awon Ogba Idera |
Ki lo mu awon ti ko gbagbo ti ara won ko bale niwaju re |
ti won si jokoo ni isori isori si owo otun ati owo osi (re) |
أَيَطْمَعُ كُلُّ امْرِئٍ مِّنْهُمْ أَن يُدْخَلَ جَنَّةَ نَعِيمٍ(38) Se eni kookan ninu won n jerankan pe A oo mu oun wo inu Ogba Idera ni |
Rara o! Dajudaju Awa seda won lati inu ohun ti won mo |
فَلَا أُقْسِمُ بِرَبِّ الْمَشَارِقِ وَالْمَغَارِبِ إِنَّا لَقَادِرُونَ(40) Nitori naa, Emi n bura pelu Oluwa awon ibuyo oorun ati awon ibuwo oorun , dajudaju Awa ni Alagbara |
عَلَىٰ أَن نُّبَدِّلَ خَيْرًا مِّنْهُمْ وَمَا نَحْنُ بِمَسْبُوقِينَ(41) lati le fi awon t’o dara ju won lo paaro won. Ko si si eni t’o le ko agara ba Wa |
فَذَرْهُمْ يَخُوضُوا وَيَلْعَبُوا حَتَّىٰ يُلَاقُوا يَوْمَهُمُ الَّذِي يُوعَدُونَ(42) Nitori naa, fi won sile ki won maa so isokuso (won), ki won si maa sere titi won yoo fi pade ojo won ti A n se ni adehun fun won |
يَوْمَ يَخْرُجُونَ مِنَ الْأَجْدَاثِ سِرَاعًا كَأَنَّهُمْ إِلَىٰ نُصُبٍ يُوفِضُونَ(43) Ojo ti won yoo sare jade werewere lati inu awon saree, won yo si da bi eni pe won n yara lo sidii ohun afojusun kan |
خَاشِعَةً أَبْصَارُهُمْ تَرْهَقُهُمْ ذِلَّةٌ ۚ ذَٰلِكَ الْيَوْمُ الَّذِي كَانُوا يُوعَدُونَ(44) Oju won yoo wale. Iyepere maa bo won mole. Ojo yen ni eyi ti A n se ni adehun fun won |
المزيد من السور باللغة اليوربا:
تحميل سورة المعارج بصوت أشهر القراء :
قم باختيار القارئ للاستماع و تحميل سورة المعارج كاملة بجودة عالية
أحمد العجمي
خالد الجليل
سعد الغامدي
سعود الشريم
عبد الباسط
عبد الله الجهني
علي الحذيفي
فارس عباد
ماهر المعيقلي
محمد جبريل
المنشاوي
الحصري
مشاري العفاسي
ناصر القطامي
ياسر الدوسري
Sunday, December 22, 2024
لا تنسنا من دعوة صالحة بظهر الغيب