La sourate Ash-Shams en Yoruba
(Allahu) bura pelu oorun ati iyaleta re |
O tun bura pelu osupa nigba ti o ba (yo) tele (oorun) |
O tun bura pelu osan nigba ti o ba mu imole ba okunkun oru |
O tun bura pelu ale nigba ti o ba bo osan mole |
O tun bura pelu sanmo ati Eni ti O mo on |
O tun bura pelu ile ati Eni ti O te e kale |
O tun bura pelu emi (eniyan) ati Eni ti O se (orikee re) dogba |
O si fi ese (ti emi le da) ati iberu re mo on |
Enikeni ti o ba safomo (emi ara) re (nibi ese), o ma ti jere |
Enikeni ti o ba fi (iwa ese) ba emi (ara) re je, o ma ti padanu |
Ijo Thamud pe ododo niro nipa itayo enu-ala won |
(Ranti) nigba ti eni ti ori re buru julo ninu won sare dide (lati gun rakunmi pa) |
فَقَالَ لَهُمْ رَسُولُ اللَّهِ نَاقَةَ اللَّهِ وَسُقْيَاهَا(13) Nigba naa, Ojise Allahu so fun won pe: "(E fi) abo rakunmi Allahu ati omi re (sile) |
فَكَذَّبُوهُ فَعَقَرُوهَا فَدَمْدَمَ عَلَيْهِمْ رَبُّهُم بِذَنبِهِمْ فَسَوَّاهَا(14) Won pe e niro. Won si gun (rakunmi) pa. Nitori naa, Oluwa won pa won re nitori ese won. O si fi iparun naa kari won |
(Eni t’o gun rakunmi pa) ko si paya ikangun oro won |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Ash-Shams : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Ash-Shams complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide