La sourate Al-Layl en Yoruba
(Allahu) bura pelu ale nigba ti (ile) ba su |
O tun bura pelu osan nigba ti (osan) ba pon |
O tun bura pelu Eni ti O da ako ati abo |
Dajudaju ise yin, otooto ni |
Ni ti eni ti o ba tore, ti o si beru (Allahu) |
(ti) o tun pe esan rere ni ododo |
A si maa se ise rere ni irorun fun un |
Ni ti eni ti o ba yahun, ti o si ri ara re leni t’o roro tayo esan orun |
(ti) o tun pe esan rere ni iro |
A si maa se ise aburu ni irorun fun un |
Dukia re ko si nii ro o loro nigba ti o ba ja bo (sinu Ina) |
Dajudaju tiWa ni (lati salaye) imona |
Ati pe dajudaju tiWa ni orun ati aye |
Nitori naa, Mo ti fi Ina elejo fofo kilo fun yin |
Ko si eni ti o maa wo inu re afi olori buruku |
eni ti o pe ododo niro, ti o si keyin si i |
Won si maa gbe (Ina) jinna si oluberu (Allahu) |
eni t’o n fi dukia re tore, ti o n safomo (re) |
Ko si si oore idera kan ti (o ni lokan) lati gba ni esan ni odo enikeni |
bi ko se pe lati fi wa oju rere Oluwa re, Eni Giga julo |
Laipe o si maa yonu (si esan re) |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Layl : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Layl complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide