La sourate At-Tariq en Yoruba
(Allahu) bura pelu sanmo ati Toriƙ |
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Toriƙ |
Irawo ti imole re n tan roro (ni ale ni) |
Ko si emi kan afi ki eso kan wa fun un (ninu awon molaika) |
Nitori naa, ki eniyan woye si ohun ti A fi seda re |
Won seda re lati inu omi t’o n tu jade kookoo |
O n jade lati aarin ibadi okunrin ati awon efonha igba-aya obinrin |
Dajudaju Allahu ni Alagbara lori idapada re |
ni ojo ti won maa se ayewo awon (ise) asepamo |
Nigba naa, ko nii si agbara tabi alaranse kan fun un |
Allahu bura pelu sanmo t’o n ro ojo ni odoodun |
O tun bura pelu ile t’o n san kankan (fun hihujade eso) |
Dajudaju al-Ƙur’an ni oro-ipinya (laaarin ododo ati iro) |
Ki i si se awada |
Dajudaju won n dete gan-an |
Emi naa si n dete gan-an |
Nitori naa, lora fun awon alaigbagbo. Lo won lara se fun igba die |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate At-Tariq : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate At-Tariq complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide