La sourate Al-Balad en Yoruba
Emi (Allahu) bura pelu ilu yii |
Iwo si ni eto si ilu yii (lati jagun ninu re) |
(Mo tun) bura pelu obi ati ohun t’o bi |
Dajudaju A seda eniyan sinu isoro |
Se o n lero pe eni kan ko ni agbara lori oun ni |
O (si) n wi pe: "Emi ti bana dukia opolopo (lati fi tako Anabi s.a.w) |
Se o n lero pe eni kan ko ri oun ni |
Se A ko se oju meji fun un |
Ati ahon pelu ete meji (ti A se fun un) |
A si fi ona meji mo on |
Ko si mu akaba igbala gun |
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je akaba igbala |
فَكُّ رَقَبَةٍ(13) (Ohun ni) titu eru sile loko eru |
Tabi fifun eniyan ni ounje ni ojo ebi |
(O le je) omo-orukan ninu ebi |
tabi mekunnu, eni ileele |
ثُمَّ كَانَ مِنَ الَّذِينَ آمَنُوا وَتَوَاصَوْا بِالصَّبْرِ وَتَوَاصَوْا بِالْمَرْحَمَةِ(17) Leyin naa, ki o wa ninu awon t’o gbagbo ni ododo, ti won n gbara won niyanju suuru sise, ti won si tun n gbara won niyanju aanu sise |
Awon wonyen ni ero owo otun |
وَالَّذِينَ كَفَرُوا بِآيَاتِنَا هُمْ أَصْحَابُ الْمَشْأَمَةِ(19) Awon t’o si sai gbagbo ninu awon ayah Wa, awon ni ero owo osi |
A maa ti awon ilekun Ina pa mo won lori patapata |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Balad : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Balad complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide