Lokman suresi çevirisi Yoruba

  1. Suresi mp3
  2. Başka bir sure
  3. Yoruba
Kuranı Kerim türkçe meali | Kur'an çevirileri | Yoruba dili | Lokman Suresi | لقمان - Ayet sayısı 34 - Moshaf'taki surenin numarası: 31 - surenin ingilizce anlamı: Luqman.

الم(1)

 ’Alif lam mim

تِلْكَ آيَاتُ الْكِتَابِ الْحَكِيمِ(2)

 Iwonyi ni awon ayah Tira ogbon

هُدًى وَرَحْمَةً لِّلْمُحْسِنِينَ(3)

 (O je) imona ati ike fun awon oluse-rere

الَّذِينَ يُقِيمُونَ الصَّلَاةَ وَيُؤْتُونَ الزَّكَاةَ وَهُم بِالْآخِرَةِ هُمْ يُوقِنُونَ(4)

 awon t’o n kirun, ti won n yo zakah. Awon si ni won ni amodaju nipa Ojo Ikeyin

أُولَٰئِكَ عَلَىٰ هُدًى مِّن رَّبِّهِمْ ۖ وَأُولَٰئِكَ هُمُ الْمُفْلِحُونَ(5)

 Awon wonyen wa lori imona lati odo Oluwa won. Awon wonyen si ni awon olujere

وَمِنَ النَّاسِ مَن يَشْتَرِي لَهْوَ الْحَدِيثِ لِيُضِلَّ عَن سَبِيلِ اللَّهِ بِغَيْرِ عِلْمٍ وَيَتَّخِذَهَا هُزُوًا ۚ أُولَٰئِكَ لَهُمْ عَذَابٌ مُّهِينٌ(6)

 O wa ninu awon eniyan, eni t’o n ra iranu-oro lati fi si awon eniyan lona kuro loju ona (esin) Allahu pelu ainimo ati nitori ki o le so esin di yeye. Awon wonyen si ni iya ti i yepere eda wa fun

وَإِذَا تُتْلَىٰ عَلَيْهِ آيَاتُنَا وَلَّىٰ مُسْتَكْبِرًا كَأَن لَّمْ يَسْمَعْهَا كَأَنَّ فِي أُذُنَيْهِ وَقْرًا ۖ فَبَشِّرْهُ بِعَذَابٍ أَلِيمٍ(7)

 Ati pe nigba ti won ba n ke awon ayah Wa fun un, o maa peyinda ni ti igberaga, afi bi eni pe ko gbo o, afi bi eni pe edidi wa ninu eti re mejeeji. Nitori naa, fun un ni iro iya eleta-elero

إِنَّ الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ لَهُمْ جَنَّاتُ النَّعِيمِ(8)

 Dajudaju awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se ise rere, awon Ogba Idera n be fun won

خَالِدِينَ فِيهَا ۖ وَعْدَ اللَّهِ حَقًّا ۚ وَهُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ(9)

 Olusegbere ni won ninu re. (O je) adehun ti Allahu se ni ti ododo. Oun si ni Alagbara, Ologbon

خَلَقَ السَّمَاوَاتِ بِغَيْرِ عَمَدٍ تَرَوْنَهَا ۖ وَأَلْقَىٰ فِي الْأَرْضِ رَوَاسِيَ أَن تَمِيدَ بِكُمْ وَبَثَّ فِيهَا مِن كُلِّ دَابَّةٍ ۚ وَأَنزَلْنَا مِنَ السَّمَاءِ مَاءً فَأَنبَتْنَا فِيهَا مِن كُلِّ زَوْجٍ كَرِيمٍ(10)

 O da awon sanmo lai ni opo ti e le ri. O si ju awon apata t’o duro gbagidi sinu ile ki o ma fi le mi mo yin lese. O fon gbogbo nnkan abemi ka sori ile. A tun so omi kale lati sanmo, A si fi mu gbogbo orisirisi eso daadaa hu jade lati inu ile

هَٰذَا خَلْقُ اللَّهِ فَأَرُونِي مَاذَا خَلَقَ الَّذِينَ مِن دُونِهِ ۚ بَلِ الظَّالِمُونَ فِي ضَلَالٍ مُّبِينٍ(11)

 Eyi ni eda ti Allahu. Nitori naa, e fi ohun ti awon miiran leyin Re da han mi! Rara o! Awon alabosi wa ninu isina ponnbele ni

وَلَقَدْ آتَيْنَا لُقْمَانَ الْحِكْمَةَ أَنِ اشْكُرْ لِلَّهِ ۚ وَمَن يَشْكُرْ فَإِنَّمَا يَشْكُرُ لِنَفْسِهِ ۖ وَمَن كَفَرَ فَإِنَّ اللَّهَ غَنِيٌّ حَمِيدٌ(12)

 Dajudaju A ti fun Luƙmon ni ogbon, pe: “Dupe fun Allahu.” Enikeni ti o ba dupe, o n dupe fun emi ara re ni. Enikeni ti o ba si sai moore, dajudaju Allahu ni Oloro, Olope (ti ope to si)

وَإِذْ قَالَ لُقْمَانُ لِابْنِهِ وَهُوَ يَعِظُهُ يَا بُنَيَّ لَا تُشْرِكْ بِاللَّهِ ۖ إِنَّ الشِّرْكَ لَظُلْمٌ عَظِيمٌ(13)

 (Ranti) nigba ti Luƙmon so fun omo re nigba ti o n se waasi fun un, pe: “Omo mi, ma se sebo si Allahu. Dajudaju ebo sise ni abosi nla

وَوَصَّيْنَا الْإِنسَانَ بِوَالِدَيْهِ حَمَلَتْهُ أُمُّهُ وَهْنًا عَلَىٰ وَهْنٍ وَفِصَالُهُ فِي عَامَيْنِ أَنِ اشْكُرْ لِي وَلِوَالِدَيْكَ إِلَيَّ الْمَصِيرُ(14)

 Ati pe A pa a ni ase fun eniyan nipa awon obi re mejeeji - iya re gbe e ka (ninu oyun) pelu ailera lori ailera, o si gba omu lenu re laaarin odun meji – (A so) pe: “Dupe fun Emi ati awon obi re mejeeji.” Odo Mi si ni abo eda

وَإِن جَاهَدَاكَ عَلَىٰ أَن تُشْرِكَ بِي مَا لَيْسَ لَكَ بِهِ عِلْمٌ فَلَا تُطِعْهُمَا ۖ وَصَاحِبْهُمَا فِي الدُّنْيَا مَعْرُوفًا ۖ وَاتَّبِعْ سَبِيلَ مَنْ أَنَابَ إِلَيَّ ۚ ثُمَّ إِلَيَّ مَرْجِعُكُمْ فَأُنَبِّئُكُم بِمَا كُنتُمْ تَعْمَلُونَ(15)

 Ti awon mejeeji ba si ja o logun pe ki o fi ohun ti iwo ko ni imo nipa re sebo si Mi, ma se tele awon mejeeji.1 Fi daadaa ba awon mejeeji lo po ni ile aye.2 Ki o si tele oju ona eni ti o ba seri pada si odo Mi (ni ti ironupiwada). Leyin naa, odo Mi ni ibupadasi yin. Nitori naa, Mo maa fun yin ni iro ohun ti e n se nise. nnkan daadaa ni. Iketa: ohunkohun ti asa ati ise eya eda kookan ba pe ni daadaa nnkan daadaa ni ni odiwon igba ti ayah kan tabi hadith kan ko ba ti lodi si irufe nnkan naa. Bi apeere

يَا بُنَيَّ إِنَّهَا إِن تَكُ مِثْقَالَ حَبَّةٍ مِّنْ خَرْدَلٍ فَتَكُن فِي صَخْرَةٍ أَوْ فِي السَّمَاوَاتِ أَوْ فِي الْأَرْضِ يَأْتِ بِهَا اللَّهُ ۚ إِنَّ اللَّهَ لَطِيفٌ خَبِيرٌ(16)

 Omo mi, dajudaju ti o ba je pe odiwon eso kardal kan lo wa ninu apata, tabi ninu awon sanmo, tabi ninu ile, Allahu yoo mu un wa. Dajudaju Allahu ni Alaaanu, Alamotan

يَا بُنَيَّ أَقِمِ الصَّلَاةَ وَأْمُرْ بِالْمَعْرُوفِ وَانْهَ عَنِ الْمُنكَرِ وَاصْبِرْ عَلَىٰ مَا أَصَابَكَ ۖ إِنَّ ذَٰلِكَ مِنْ عَزْمِ الْأُمُورِ(17)

 Omo mi, kirun, p’ase rere, ko aburu, ki o si se suuru lori ohun ti o ba sele si o. Dajudaju iyen wa ninu awon ipinnu oro t’o pon dandan

وَلَا تُصَعِّرْ خَدَّكَ لِلنَّاسِ وَلَا تَمْشِ فِي الْأَرْضِ مَرَحًا ۖ إِنَّ اللَّهَ لَا يُحِبُّ كُلَّ مُخْتَالٍ فَخُورٍ(18)

 Ma se ko parike re si eniyan. Ma si se rin lori ile pelu faari. Dajudaju Allahu ko feran gbogbo onigbeeraga, onifaari

وَاقْصِدْ فِي مَشْيِكَ وَاغْضُضْ مِن صَوْتِكَ ۚ إِنَّ أَنكَرَ الْأَصْوَاتِ لَصَوْتُ الْحَمِيرِ(19)

 Je ki irin ese re wa ni iwontun-wonsi, ki o si re ohun re nile. Dajudaju ohun t’o buru julo ma ni ohun ketekete.”

أَلَمْ تَرَوْا أَنَّ اللَّهَ سَخَّرَ لَكُم مَّا فِي السَّمَاوَاتِ وَمَا فِي الْأَرْضِ وَأَسْبَغَ عَلَيْكُمْ نِعَمَهُ ظَاهِرَةً وَبَاطِنَةً ۗ وَمِنَ النَّاسِ مَن يُجَادِلُ فِي اللَّهِ بِغَيْرِ عِلْمٍ وَلَا هُدًى وَلَا كِتَابٍ مُّنِيرٍ(20)

 Se e o ri i pe dajudaju Allahu ro ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ohunkohun t’o wa ninu ile fun yin, O si pe awon ike Re fun yin ni gbangba ati ni koro? O si wa ninu awon eniyan eni t’o n jiyan nipa Allahu lai ni imo (al-Ƙur’an) ati imona (ninu sunnah Anabi s.a.w.) ati tira (onimo-esin) t’o n tan imole (si oro esin)

وَإِذَا قِيلَ لَهُمُ اتَّبِعُوا مَا أَنزَلَ اللَّهُ قَالُوا بَلْ نَتَّبِعُ مَا وَجَدْنَا عَلَيْهِ آبَاءَنَا ۚ أَوَلَوْ كَانَ الشَّيْطَانُ يَدْعُوهُمْ إِلَىٰ عَذَابِ السَّعِيرِ(21)

 Nigba ti won ba si so fun won pe: “E tele ohun ti Allahu sokale.” Won a wi pe: “Rara! A maa tele ohun ti a ba lowo awon baba wa ni.” (Se won yoo tele awon baba won) t’ohun ti bi Esu se n pe won sibi iya Ina t’o n jo fofo

۞ وَمَن يُسْلِمْ وَجْهَهُ إِلَى اللَّهِ وَهُوَ مُحْسِنٌ فَقَدِ اسْتَمْسَكَ بِالْعُرْوَةِ الْوُثْقَىٰ ۗ وَإِلَى اللَّهِ عَاقِبَةُ الْأُمُورِ(22)

 Enikeni ti o ba jura re sile fun Allahu, ti o je oluse-rere, dajudaju onitoun ti diro mo okun t’o fokan bale julo. Ati pe odo Allahu ni ikangun awon oro (eda)

وَمَن كَفَرَ فَلَا يَحْزُنكَ كُفْرُهُ ۚ إِلَيْنَا مَرْجِعُهُمْ فَنُنَبِّئُهُم بِمَا عَمِلُوا ۚ إِنَّ اللَّهَ عَلِيمٌ بِذَاتِ الصُّدُورِ(23)

 Enikeni ti o ba si sai gbagbo, ma se je ki aigbagbo re ko ibanuje ba o. Odo Wa ni ibupadasi won. Nigba naa, A maa fun won ni iro ohun ti won se nise. Dajudaju Allahu ni Onimo nipa ohun ti n be ninu igba-aya eda

نُمَتِّعُهُمْ قَلِيلًا ثُمَّ نَضْطَرُّهُمْ إِلَىٰ عَذَابٍ غَلِيظٍ(24)

 A maa fun won ni igbadun die. Leyin naa, A maa taari won sinu iya t’o nipon

وَلَئِن سَأَلْتَهُم مَّنْ خَلَقَ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضَ لَيَقُولُنَّ اللَّهُ ۚ قُلِ الْحَمْدُ لِلَّهِ ۚ بَلْ أَكْثَرُهُمْ لَا يَعْلَمُونَ(25)

 Dajudaju ti o ba bi won leere pe: “Ta ni O da awon sanmo ati ile?”, dajudaju won a wi pe: “Allahu ni.” So pe: “Gbogbo ope n je ti Allahu, sugbon opolopo won ko mo

لِلَّهِ مَا فِي السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ ۚ إِنَّ اللَّهَ هُوَ الْغَنِيُّ الْحَمِيدُ(26)

 Ti Allahu ni ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ile. Dajudaju Allahu, Oun ni Oloro, Olope

وَلَوْ أَنَّمَا فِي الْأَرْضِ مِن شَجَرَةٍ أَقْلَامٌ وَالْبَحْرُ يَمُدُّهُ مِن بَعْدِهِ سَبْعَةُ أَبْحُرٍ مَّا نَفِدَتْ كَلِمَاتُ اللَّهِ ۗ إِنَّ اللَّهَ عَزِيزٌ حَكِيمٌ(27)

 Ti o ba je pe kikida ohun t’o n be lori ile ni igi ni gege ikowe, ki agbami odo je tadaa re, agbami odo meje (tun wa) leyin re (t’o maa kun un), awon oro Allahu ko nii tan (leyin ti awon nnkan ikowe wonyi ba tan nile). Dajudaju Allahu ni Alagbara, Ologbon

مَّا خَلْقُكُمْ وَلَا بَعْثُكُمْ إِلَّا كَنَفْسٍ وَاحِدَةٍ ۗ إِنَّ اللَّهَ سَمِيعٌ بَصِيرٌ(28)

 Iseda yin ati ajinde yin ko tayo bi (iseda ati ajinde) emi eyo kan. Dajudaju Allahu ni Olugbo, Oluriran

أَلَمْ تَرَ أَنَّ اللَّهَ يُولِجُ اللَّيْلَ فِي النَّهَارِ وَيُولِجُ النَّهَارَ فِي اللَّيْلِ وَسَخَّرَ الشَّمْسَ وَالْقَمَرَ كُلٌّ يَجْرِي إِلَىٰ أَجَلٍ مُّسَمًّى وَأَنَّ اللَّهَ بِمَا تَعْمَلُونَ خَبِيرٌ(29)

 Se o o ri i pe dajudaju Allahu l’O n ti oru bo inu osan, O n ti osan bo inu oru, O si ro oorun ati osupa? Ikookan won si n rin titi di gbedeke akoko kan. Ati pe (se o o ri i pe) dajudaju Allahu ni Alamotan nipa ohun ti e n se nise

ذَٰلِكَ بِأَنَّ اللَّهَ هُوَ الْحَقُّ وَأَنَّ مَا يَدْعُونَ مِن دُونِهِ الْبَاطِلُ وَأَنَّ اللَّهَ هُوَ الْعَلِيُّ الْكَبِيرُ(30)

 Iyen nitori pe, dajudaju Allahu, Oun ni Ododo. Ati pe dajudaju ohun ti won n pe leyin Re ni iro. Dajudaju Allahu, O ga, O tobi

أَلَمْ تَرَ أَنَّ الْفُلْكَ تَجْرِي فِي الْبَحْرِ بِنِعْمَتِ اللَّهِ لِيُرِيَكُم مِّنْ آيَاتِهِ ۚ إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَآيَاتٍ لِّكُلِّ صَبَّارٍ شَكُورٍ(31)

 Se o o ri i pe dajudaju oko oju-omi n rin ni oju omi pelu idera Re, (sebi) nitori ki (Allahu) le fi han yin ninu awon ami Re ni? Dajudaju awon ami wa ninu iyen fun gbogbo onisuuru, oludupe

وَإِذَا غَشِيَهُم مَّوْجٌ كَالظُّلَلِ دَعَوُا اللَّهَ مُخْلِصِينَ لَهُ الدِّينَ فَلَمَّا نَجَّاهُمْ إِلَى الْبَرِّ فَمِنْهُم مُّقْتَصِدٌ ۚ وَمَا يَجْحَدُ بِآيَاتِنَا إِلَّا كُلُّ خَتَّارٍ كَفُورٍ(32)

 Nigba ti igbi omi ba bo won mole daru bi awon apata ati esujo, won a pe Allahu (gege bi) olusafomo-adua fun Un. Nigba ti O ba si gba won la sori ile, onideede si maa wa ninu won. Ko si si eni t’o maa tako awon ayah Wa afi gbogbo odale, alaimoore

يَا أَيُّهَا النَّاسُ اتَّقُوا رَبَّكُمْ وَاخْشَوْا يَوْمًا لَّا يَجْزِي وَالِدٌ عَن وَلَدِهِ وَلَا مَوْلُودٌ هُوَ جَازٍ عَن وَالِدِهِ شَيْئًا ۚ إِنَّ وَعْدَ اللَّهِ حَقٌّ ۖ فَلَا تَغُرَّنَّكُمُ الْحَيَاةُ الدُّنْيَا وَلَا يَغُرَّنَّكُم بِاللَّهِ الْغَرُورُ(33)

 Eyin eniyan, e beru Oluwa yin. Ki e si paya ojo kan ti obi kan ko nii sanfaani fun omo re; ati pe omo kan, oun naa ko nii sanfaani kini kan fun obi re. Dajudaju adehun Allahu ni ododo. Nitori naa, isemi aye yii ko gbodo tan yin je. (Esu) eletan ko si gbodo tan yin je nipa Allahu

إِنَّ اللَّهَ عِندَهُ عِلْمُ السَّاعَةِ وَيُنَزِّلُ الْغَيْثَ وَيَعْلَمُ مَا فِي الْأَرْحَامِ ۖ وَمَا تَدْرِي نَفْسٌ مَّاذَا تَكْسِبُ غَدًا ۖ وَمَا تَدْرِي نَفْسٌ بِأَيِّ أَرْضٍ تَمُوتُ ۚ إِنَّ اللَّهَ عَلِيمٌ خَبِيرٌ(34)

 Dajudaju Allahu, odo Re ni imo Akoko naa wa. O n so ojo kale. O mo ohun t’o wa ninu apoluke. Emi kan ko si mo ohun ti o maa se nise ni ola. Emi kan ko si mo ile wo l’o maa ku si. Dajudaju Allahu ni Onimo, Alamotan


Yoruba diğer sureler:

Bakara suresi Âl-i İmrân Nisâ suresi
Mâide suresi Yûsuf suresi İbrâhîm suresi
Hicr suresi Kehf suresi Meryem suresi
Hac suresi Kasas suresi Ankebût suresi
As-Sajdah Yâsîn suresi Duhân suresi
fetih suresi Hucurât suresi Kâf suresi
Necm suresi Rahmân suresi vakıa suresi
Haşr suresi Mülk suresi Hâkka suresi
İnşikâk suresi Alâ suresi Gâşiye suresi

En ünlü okuyucuların sesiyle Lokman Suresi indirin:

Surah Luqman mp3: yüksek kalitede dinlemek ve indirmek için okuyucuyu seçerek
Lokman Suresi Ahmed El Agamy
Ahmed El Agamy
Lokman Suresi Saad Al Ghamdi
Saad Al Ghamdi
Lokman Suresi Saud Al Shuraim
Saud Al Shuraim
Lokman Suresi Abdul Basit Abdul Samad
Abdul Basit
Lokman Suresi Abdullah Basfar
Abdullah Basfar
Lokman Suresi Abdullah Awwad Al Juhani
Abdullah Al Juhani
Lokman Suresi Ali Al Hudhaifi
Ali Al Hudhaifi
Lokman Suresi Fares Abbad
Fares Abbad
Lokman Suresi Maher Al Muaiqly
Maher Al Muaiqly
Lokman Suresi Muhammad Jibril
Muhammad Jibril
Lokman Suresi Muhammad Siddiq Al Minshawi
Al Minshawi
Lokman Suresi Al Hosary
Al Hosary
Lokman Suresi Al-afasi
Mishari Al-afasi
Lokman Suresi Nasser Al Qatami
Nasser Al Qatami
Lokman Suresi Yasser Al Dosari
Yasser Al Dosari


Sunday, December 22, 2024

Bizim için dua et, teşekkürler