Hakka suresi çevirisi Yoruba
الْحَاقَّةُ(1) Isele Ododo |
Ki ni Isele Ododo |
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Isele Ododo |
Awon ijo Thamud ati ijo ‘Ad pe Ipaya niro |
Ni ti ijo Thamud, won fi igbe t’o tayo enu-ala pa won re |
Ni ti ijo ‘Ad, won fi ategun lile t’o tayo enu-ala pa won re |
O de e si won fun oru meje ati osan mejo lai dawo duro. O si maa ri ijo naa ti won ti ku sinu re bi eni pe kukute igi dabinu t’o ti luho ninu ni won |
Nje o ri eni kan ninu won t’o se ku bi |
وَجَاءَ فِرْعَوْنُ وَمَن قَبْلَهُ وَالْمُؤْتَفِكَاتُ بِالْخَاطِئَةِ(9) Fir‘aon ati awon t’o siwaju re ati awon ilu ti won doju re bole de pelu awon asise |
فَعَصَوْا رَسُولَ رَبِّهِمْ فَأَخَذَهُمْ أَخْذَةً رَّابِيَةً(10) Won yapa Ojise Oluwa won. O si gba won mu ni igbamu alekun |
إِنَّا لَمَّا طَغَى الْمَاءُ حَمَلْنَاكُمْ فِي الْجَارِيَةِ(11) Dajudaju nigba ti omi tayo enu-ala. A gbe yin gun oko oju-omi |
لِنَجْعَلَهَا لَكُمْ تَذْكِرَةً وَتَعِيَهَا أُذُنٌ وَاعِيَةٌ(12) Nitori ki A le fi se iranti fun yin ati nitori ki eti t’o n so nnkan le so o |
Nigba ti won ba fon fere oniwo fun iku ni fifon eyo kan |
وَحُمِلَتِ الْأَرْضُ وَالْجِبَالُ فَدُكَّتَا دَكَّةً وَاحِدَةً(14) ti won gbe ile ati apata soke, ti won si run mejeeji womuwomu ni rirun ee kan |
ni ojo yen ni Isele maa sele |
Ati pe sanmo yo faya perepere. O si maa fuye gege ni ojo yen |
وَالْمَلَكُ عَلَىٰ أَرْجَائِهَا ۚ وَيَحْمِلُ عَرْشَ رَبِّكَ فَوْقَهُمْ يَوْمَئِذٍ ثَمَانِيَةٌ(17) Awon molaika si maa wa ni awon egbeegbe re. Ati pe ni ojo yen, loke won, awon (molaika) mejo ni won maa ru Ite Oluwa re |
Ni ojo yen, won yoo maa seri yin wa (fun isiro-ise). Ko si nii si asiri yin kan t’o maa pamo (fun Wa) |
فَأَمَّا مَنْ أُوتِيَ كِتَابَهُ بِيَمِينِهِ فَيَقُولُ هَاؤُمُ اقْرَءُوا كِتَابِيَهْ(19) Nitori naa, ni ti eni ti won ba fun ni tira re ni owo otun re, o maa so pe: "E gba, e ka tira mi |
Dajudaju emi ti mo amodaju pe dajudaju emi yoo ba isiro-ise mi pade |
Nitori naa, o maa wa ninu isemi t’o maa yonu si |
ninu Ogba Idera giga |
Awon eso re (si) wa ni arowoto |
كُلُوا وَاشْرَبُوا هَنِيئًا بِمَا أَسْلَفْتُمْ فِي الْأَيَّامِ الْخَالِيَةِ(24) E je, ki e si mu pelu igbadun nitori ohun ti e ti siwaju ninu awon ojo ti o ti re koja |
وَأَمَّا مَنْ أُوتِيَ كِتَابَهُ بِشِمَالِهِ فَيَقُولُ يَا لَيْتَنِي لَمْ أُوتَ كِتَابِيَهْ(25) Ni ti eni ti won ba si fun ni tira re ni owo osi re, o maa wi pe: "Haa! Ki won si ma fun mi ni tira mi! mejeeji lo maa sele si won nitori pe owo osi ni alaigbagbo maa ti bo inu igba-aya re bo si eyin re lati fi gba iwe ise re |
Ati pe emi ko mo ohun ti isiro-ise mi je |
Haa! Ki iku si je opin (oro eda) |
Dukia mi ko si ro mi loro |
Agbara mi si ti parun |
E mu un, ki e de e ni owo mo orun |
Leyin naa, inu ina Jehim ni ki e mu un wo |
ثُمَّ فِي سِلْسِلَةٍ ذَرْعُهَا سَبْعُونَ ذِرَاعًا فَاسْلُكُوهُ(32) Leyin naa, inu ewon ti gigun re je aadorin gigun thar‘u ni ki e ki i si |
Dajudaju oun ki i gbagbo ninu Allahu, Atobi |
Ki i si gba eniyan niyanju lati bo awon mekunnu |
Nitori naa, ko nii si ore imule kan fun un nibi yii ni oni |
Ko si nii si ounje kan (fun un) bi ko se (ounje) awoyunweje |
Ko si eni ti o maa je e bi ko se awon elese |
Nitori naa, Emi n bura pelu ohun ti e n foju ri |
ati ohun ti e o foju ri |
Dajudaju al-Ƙur’an ni oro (ti A fi ran) Ojise, alapon-onle |
Ki i se oro elewi. Ohun ti e gbagbo kere pupo |
Ki i si se oro adabigba. Die le n lo ninu iranti |
Won so o kale lati odo Oluwa gbogbo eda |
Ti o ba je pe (Anabi) da adapa apa kan oro naa mo Wa ni |
Awa iba gba a mu lowo otun |
Leyin naa, Awa iba ja isan orun re |
Ko si si eni kan ninu yin ti o maa gba a sile lowo (Wa) |
Dajudaju (al-Ƙur’an) ni iranti fun awon oluberu (Allahu) |
Dajudaju Awa si mo pe awon t’o n pe al-Ƙur’an niro wa ninu yin |
Dajudaju al-Ƙur’an maa je abamo fun awon alaigbagbo |
Dajudaju al-Ƙur’an ni ododo t’o daju |
Nitori naa, safomo fun oruko Oluwa Re, Atobi |
Yoruba diğer sureler:
En ünlü okuyucuların sesiyle Hakka Suresi indirin:
Surah Al-Haqqah mp3: yüksek kalitede dinlemek ve indirmek için okuyucuyu seçerek
Ahmed El Agamy
Saad Al Ghamdi
Saud Al Shuraim
Abdul Basit
Abdullah Basfar
Abdullah Al Juhani
Ali Al Hudhaifi
Fares Abbad
Maher Al Muaiqly
Muhammad Jibril
Al Minshawi
Al Hosary
Mishari Al-afasi
Nasser Al Qatami
Yasser Al Dosari
Bizim için dua et, teşekkürler