La sourate Al-Ala en Yoruba
Safomo fun oruko Oluwa re, Eni giga julo |
Eni ti O da eda. O si se (orikee-rikee re) ni dogbadogba |
Eni ti O yan kadara (fun eda). O si to o sona |
Eni ti O mu koriko tutu (hu) jade |
O si so o di gbigbe t’o dudu |
Awa yoo maa ke (al-Ƙur’an) fun o. Iwo ko si nii gbagbe |
إِلَّا مَا شَاءَ اللَّهُ ۚ إِنَّهُ يَعْلَمُ الْجَهْرَ وَمَا يَخْفَىٰ(7) Ayafi ohun ti Allahu ba fe. Dajudaju O mo gbangba ati ohun t’o pamo |
Awa yo si se ise rere ni irorun fun o |
Nitori naa, seranti ni aye ti iranti ti wulo |
Eni ti o maa paya (Allahu) maa lo iranti |
Olori-buruku si maa takete si i |
(Oun si ni) eni ti o maa wo inu Ina t’o tobi |
Leyin naa, ko nii ku sinu re, ko si nii semi (alaafia) |
Dajudaju eni ti o ba safomo (okan re) ti jere |
O tun ranti oruko Oluwa re, o si kirun |
Rara, nse l’e n gbe ajulo fun isemi aye |
Orun si loore julo, o si maa wa titi laelae |
Dajudaju eyi wa ninu awon takada akoko |
takada (Anabi) ’Ibrohim ati (Anabi) Musa |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Ala : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Ala complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide