Abese suresi çevirisi Yoruba

  1. Suresi mp3
  2. Başka bir sure
  3. Yoruba
Kuranı Kerim türkçe meali | Kur'an çevirileri | Yoruba dili | Abese Suresi | عبس - Ayet sayısı 42 - Moshaf'taki surenin numarası: 80 - surenin ingilizce anlamı: He Frowned.

عَبَسَ وَتَوَلَّىٰ(1)

 (Anabi s.a.w.) faju ro, o si peyin da

أَن جَاءَهُ الْأَعْمَىٰ(2)

 nitori pe afoju wa ba a

وَمَا يُدْرِيكَ لَعَلَّهُ يَزَّكَّىٰ(3)

 Ki si l’o maa fi mo o pe o see se ki o safomo (ara re kuro ninu aigbagbo)

أَوْ يَذَّكَّرُ فَتَنفَعَهُ الذِّكْرَىٰ(4)

 tabi ki o gbo iranti, ki iranti naa si se e ni anfaani

أَمَّا مَنِ اسْتَغْنَىٰ(5)

 Ni ti eni ti o ka ara re kun oloro

فَأَنتَ لَهُ تَصَدَّىٰ(6)

 oun ni iwo teti si

وَمَا عَلَيْكَ أَلَّا يَزَّكَّىٰ(7)

 Ko si si ese fun o bi ko ba se afomo (ara re kuro ninu aigbagbo)

وَأَمَّا مَن جَاءَكَ يَسْعَىٰ(8)

 Ni ti eni ti o si wa ba o, t’o n yara gaga (si iranti, iyen afoju)

وَهُوَ يَخْشَىٰ(9)

 ti o si n paya (Allahu)

فَأَنتَ عَنْهُ تَلَهَّىٰ(10)

 iwo ko si kobi ara si i

كَلَّا إِنَّهَا تَذْكِرَةٌ(11)

 Rara (ko to bee). Dajudaju al-Ƙur’an ni iranti

فَمَن شَاءَ ذَكَرَهُ(12)

 Nitori naa, eni ti o ba fe ki o ranti re

فِي صُحُفٍ مُّكَرَّمَةٍ(13)

 (Al-Ƙur’an) wa ninu awon takada alapon-onle

مَّرْفُوعَةٍ مُّطَهَّرَةٍ(14)

 A gbe e ga, A si se e ni mimo

بِأَيْدِي سَفَرَةٍ(15)

 ni owo awon onkotia (iyen, awon molaika)

كِرَامٍ بَرَرَةٍ(16)

 awon alapon-onle, awon eni rere

قُتِلَ الْإِنسَانُ مَا أَكْفَرَهُ(17)

 Won ti fi eniyan gegun-un (nipa) bi o se je alaimoore julo

مِنْ أَيِّ شَيْءٍ خَلَقَهُ(18)

 Ki si ni Allahu fi seda re

مِن نُّطْفَةٍ خَلَقَهُ فَقَدَّرَهُ(19)

 Ninu ato l’O ti seda re. O si pebubu (eya-ara) re

ثُمَّ السَّبِيلَ يَسَّرَهُ(20)

 Leyin naa, O se ona atiwaye ni irorun fun un

ثُمَّ أَمَاتَهُ فَأَقْبَرَهُ(21)

 Leyin naa, O maa pa a. O si maa fi sinu saree

ثُمَّ إِذَا شَاءَ أَنشَرَهُ(22)

 Leyin naa, nigba ti Allahu ba fe, O maa gbe e dide

كَلَّا لَمَّا يَقْضِ مَا أَمَرَهُ(23)

 E gbo, eniyan ko ti i se nnkan ti Allahu pa lase fun un

فَلْيَنظُرِ الْإِنسَانُ إِلَىٰ طَعَامِهِ(24)

 Nitori naa, ki eniyan woye si ounje re

أَنَّا صَبَبْنَا الْمَاءَ صَبًّا(25)

 Dajudaju Awa n ro ojo ni pupo

ثُمَّ شَقَقْنَا الْأَرْضَ شَقًّا(26)

 Leyin naa, A mu ile san kankan

فَأَنبَتْنَا فِيهَا حَبًّا(27)

 A si mu koro eso hu jade lati inu re

وَعِنَبًا وَقَضْبًا(28)

 ati eso ajara ati kannafuru

وَزَيْتُونًا وَنَخْلًا(29)

 ati igi ororo Zaetun ati dabinu

وَحَدَائِقَ غُلْبًا(30)

 ati awon ogba t’o kun fun igi

وَفَاكِهَةً وَأَبًّا(31)

 ati awon eso (miiran) pelu ewe ti eranko n je, (A mu won hu jade)

مَّتَاعًا لَّكُمْ وَلِأَنْعَامِكُمْ(32)

 (Won je nnkan) igbadun fun eyin ati awon eran-osin yin

فَإِذَا جَاءَتِ الصَّاخَّةُ(33)

 Nigba ti fifon sinu iwo nigba keji ba sele

يَوْمَ يَفِرُّ الْمَرْءُ مِنْ أَخِيهِ(34)

 ni ojo ti eniyan yoo sa fun arakunrin re

وَأُمِّهِ وَأَبِيهِ(35)

 ati iya re pelu baba re

وَصَاحِبَتِهِ وَبَنِيهِ(36)

 ati iyawo re pelu awon omo re

لِكُلِّ امْرِئٍ مِّنْهُمْ يَوْمَئِذٍ شَأْنٌ يُغْنِيهِ(37)

 Eni kookan won ni ojo yen l’o ti ni oran t’o maa to o o ran

وُجُوهٌ يَوْمَئِذٍ مُّسْفِرَةٌ(38)

 Awon oju kan lojo yen yoo mole

ضَاحِكَةٌ مُّسْتَبْشِرَةٌ(39)

 Won yo maa rerin-in, won yo si maa dunnu

وَوُجُوهٌ يَوْمَئِذٍ عَلَيْهَا غَبَرَةٌ(40)

 Awon oju kan lojo yen ni eruku yo si bo mole

تَرْهَقُهَا قَتَرَةٌ(41)

 Okunkun yo si bo won mole

أُولَٰئِكَ هُمُ الْكَفَرَةُ الْفَجَرَةُ(42)

 Awon wonyen, awon ni alaigbagbo, elese


Yoruba diğer sureler:

Bakara suresi Âl-i İmrân Nisâ suresi
Mâide suresi Yûsuf suresi İbrâhîm suresi
Hicr suresi Kehf suresi Meryem suresi
Hac suresi Kasas suresi Ankebût suresi
As-Sajdah Yâsîn suresi Duhân suresi
fetih suresi Hucurât suresi Kâf suresi
Necm suresi Rahmân suresi vakıa suresi
Haşr suresi Mülk suresi Hâkka suresi
İnşikâk suresi Alâ suresi Gâşiye suresi

En ünlü okuyucuların sesiyle Abese Suresi indirin:

Surah Abasa mp3: yüksek kalitede dinlemek ve indirmek için okuyucuyu seçerek
Abese Suresi Ahmed El Agamy
Ahmed El Agamy
Abese Suresi Saad Al Ghamdi
Saad Al Ghamdi
Abese Suresi Saud Al Shuraim
Saud Al Shuraim
Abese Suresi Abdul Basit Abdul Samad
Abdul Basit
Abese Suresi Abdullah Basfar
Abdullah Basfar
Abese Suresi Abdullah Awwad Al Juhani
Abdullah Al Juhani
Abese Suresi Ali Al Hudhaifi
Ali Al Hudhaifi
Abese Suresi Fares Abbad
Fares Abbad
Abese Suresi Maher Al Muaiqly
Maher Al Muaiqly
Abese Suresi Muhammad Jibril
Muhammad Jibril
Abese Suresi Muhammad Siddiq Al Minshawi
Al Minshawi
Abese Suresi Al Hosary
Al Hosary
Abese Suresi Al-afasi
Mishari Al-afasi
Abese Suresi Nasser Al Qatami
Nasser Al Qatami
Abese Suresi Yasser Al Dosari
Yasser Al Dosari


Saturday, May 18, 2024

Bizim için dua et, teşekkürler