La sourate Al-Hijr en Yoruba
’Alif lam ro. Iwonyi ni awon ayah Tira naa ati (awon ayah) al-Ƙur’an t’o n yanju oro eda |
رُّبَمَا يَوَدُّ الَّذِينَ كَفَرُوا لَوْ كَانُوا مُسْلِمِينَ(2) O see se ki awon t’o sai gbagbo nifee si pe awon iba si ti je musulumi (nile aye) |
ذَرْهُمْ يَأْكُلُوا وَيَتَمَتَّعُوا وَيُلْهِهِمُ الْأَمَلُ ۖ فَسَوْفَ يَعْلَمُونَ(3) Fi won sile, ki won je, ki won gbadun, ki ireti (emi gigun) ko airoju raaye ba won (lati sesin); laipe won maa mo |
وَمَا أَهْلَكْنَا مِن قَرْيَةٍ إِلَّا وَلَهَا كِتَابٌ مَّعْلُومٌ(4) A ko pa ilu kan run ri afi ki o ni akosile ti A ti mo |
مَّا تَسْبِقُ مِنْ أُمَّةٍ أَجَلَهَا وَمَا يَسْتَأْخِرُونَ(5) Ko si ijo kan (ti o parun) siwaju akoko re (ninu Laohul-Mahfuuth); won ko si nii sun un siwaju fun won |
وَقَالُوا يَا أَيُّهَا الَّذِي نُزِّلَ عَلَيْهِ الذِّكْرُ إِنَّكَ لَمَجْنُونٌ(6) Won wi pe: “Iwo ti Won so al-Ƙur’an kale fun, dajudaju were ni e |
لَّوْ مَا تَأْتِينَا بِالْمَلَائِكَةِ إِن كُنتَ مِنَ الصَّادِقِينَ(7) Ki ni ko je ki iwo mu awon molaika wa ba wa, ti iwo ba wa ninu awon olododo?” |
مَا نُنَزِّلُ الْمَلَائِكَةَ إِلَّا بِالْحَقِّ وَمَا كَانُوا إِذًا مُّنظَرِينَ(8) A o nii so molaika kale bi ko se pelu ododo. Won ko si nii lo won lara mo nigba naa (ti awon molaika ba sokale) |
إِنَّا نَحْنُ نَزَّلْنَا الذِّكْرَ وَإِنَّا لَهُ لَحَافِظُونَ(9) Dajudaju Awa l’A so Tira Iranti kale (iyen al-Ƙur’an). Dajudaju Awa si ni Oluso re |
وَلَقَدْ أَرْسَلْنَا مِن قَبْلِكَ فِي شِيَعِ الْأَوَّلِينَ(10) Dajudaju siwaju re A ti ran (awon Ojise) nise si awon ijo, awon eni akoko |
وَمَا يَأْتِيهِم مِّن رَّسُولٍ إِلَّا كَانُوا بِهِ يَسْتَهْزِئُونَ(11) Ojise kan ko si nii de ba won afi ki won fi se yeye |
Bayen ni A se n fi (aisan) sinu okan awon elese |
لَا يُؤْمِنُونَ بِهِ ۖ وَقَدْ خَلَتْ سُنَّةُ الْأَوَّلِينَ(13) Won ko nii gba Anabi (sollalahu alayhi wa sallam) gbo; ise (Allahu lori) awon eni akoko kuku ti re koja |
وَلَوْ فَتَحْنَا عَلَيْهِم بَابًا مِّنَ السَّمَاءِ فَظَلُّوا فِيهِ يَعْرُجُونَ(14) Ti o ba je pe A si ilekun kan sile fun won lati inu sanmo, ti won ko si ye gbabe gunke lo (sinu sanmo) |
لَقَالُوا إِنَّمَا سُكِّرَتْ أَبْصَارُنَا بَلْ نَحْنُ قَوْمٌ مَّسْحُورُونَ(15) dajudaju won a wi pe: “Won kuku lo isiju fun wa ni. Nse ni won n dan wa.” |
وَلَقَدْ جَعَلْنَا فِي السَّمَاءِ بُرُوجًا وَزَيَّنَّاهَا لِلنَّاظِرِينَ(16) A kuku fi awon ibuso (irawo) sinu sanmo (aye). A si se e ni oso fun awon oluworan |
A si fi aabo bo imisi sanmo lodo gbogbo esu, eni eko |
إِلَّا مَنِ اسْتَرَقَ السَّمْعَ فَأَتْبَعَهُ شِهَابٌ مُّبِينٌ(18) Afi (esu) ti o ba ji oro gbo. Nigba naa si ni ogunna ponnbele yo tele e lati eyin |
Ile, A te e perese. A si ju awon apata t’o duro gbagidi sinu re. A si mu gbogbo nnkan ti o ni odiwon hu jade lati inu re |
وَجَعَلْنَا لَكُمْ فِيهَا مَعَايِشَ وَمَن لَّسْتُمْ لَهُ بِرَازِقِينَ(20) A se ona ije-imu sinu (ile aye) fun eyin ati awon ti eyin ko le pese fun |
وَإِن مِّن شَيْءٍ إِلَّا عِندَنَا خَزَائِنُهُ وَمَا نُنَزِّلُهُ إِلَّا بِقَدَرٍ مَّعْلُومٍ(21) Ko si si kini kan afi ki ile-oro re wa lodo Wa. Awa ko si nii so o kale afi pelu odiwon ti A ti mo |
Ati pe A ran ategun lati ko esujo jo. A si so omi kale lati sanmo. Nitori naa, A fun yin mu. Eyin si ko ni e ko omi ojo jo (soju sanmo) |
وَإِنَّا لَنَحْنُ نُحْيِي وَنُمِيتُ وَنَحْنُ الْوَارِثُونَ(23) Dajudaju Awa, Awa ma l’A n so (eda) di alaaye. A si n so o di oku. Awa si ni A oo jogun (eda) |
وَلَقَدْ عَلِمْنَا الْمُسْتَقْدِمِينَ مِنكُمْ وَلَقَدْ عَلِمْنَا الْمُسْتَأْخِرِينَ(24) Ati pe dajudaju A mo awon olugbawaju ninu yin. Dajudaju A si mo awon olugbeyin |
وَإِنَّ رَبَّكَ هُوَ يَحْشُرُهُمْ ۚ إِنَّهُ حَكِيمٌ عَلِيمٌ(25) Dajudaju Oluwa re, Oun l’O maa ko won jo. Dajudaju Oun ni Ologbon, Onimo |
وَلَقَدْ خَلَقْنَا الْإِنسَانَ مِن صَلْصَالٍ مِّنْ حَمَإٍ مَّسْنُونٍ(26) Dajudaju A seda eniyan lati ara amo t’o n dun koko, t’o ti pawoda |
وَالْجَانَّ خَلَقْنَاهُ مِن قَبْلُ مِن نَّارِ السَّمُومِ(27) Ati pe alujannu, A seda re siwaju (eniyan) lati ara ina alategun gbigbona ti ko ni eefin |
وَإِذْ قَالَ رَبُّكَ لِلْمَلَائِكَةِ إِنِّي خَالِقٌ بَشَرًا مِّن صَلْصَالٍ مِّنْ حَمَإٍ مَّسْنُونٍ(28) (Ranti) nigba ti Oluwa re so fun awon molaika pe: “Dajudaju Emi yoo se eda abara kan lati ara amo t’o n dun koko, t’o ti pawoda |
فَإِذَا سَوَّيْتُهُ وَنَفَخْتُ فِيهِ مِن رُّوحِي فَقَعُوا لَهُ سَاجِدِينَ(29) Nigba ti Mo ba se e t’o gun rege tan, ti Mo fe emi si i (lara) ninu emi Mi (ti Mo da), nigba naa e doju bole fun un ni oluforikanle-kini |
Nitori naa, awon molaika, gbogbo won patapata si fori kanle ki i |
Ayafi ’Iblis. O ko lati wa ninu awon oluforikanle naa |
قَالَ يَا إِبْلِيسُ مَا لَكَ أَلَّا تَكُونَ مَعَ السَّاجِدِينَ(32) (Allahu) so pe: "’Iblis, ki l’o di o lowo lati wa ninu awon oluforikanle |
قَالَ لَمْ أَكُن لِّأَسْجُدَ لِبَشَرٍ خَلَقْتَهُ مِن صَلْصَالٍ مِّنْ حَمَإٍ مَّسْنُونٍ(33) O wi pe: "Emi ko nii fori kanle ki abara kan ti O seda re lati ara amo t’o n dun koko, t’o ti pawoda |
(Allahu) so pe: "Nitori naa, jade kuro ninu re. Dajudaju, iwo ni eni-eko |
Ati pe, dajudaju egun n be lori re titi di Ojo esan |
O wi pe: “Oluwa mi, lo mi lara titi di Ojo Ajinde.” |
(Allahu) so pe: "Dajudaju iwo wa lara awon ti A oo lo lara |
titi di ojo akoko ti A ti mo |
قَالَ رَبِّ بِمَا أَغْوَيْتَنِي لَأُزَيِّنَنَّ لَهُمْ فِي الْأَرْضِ وَلَأُغْوِيَنَّهُمْ أَجْمَعِينَ(39) O wi pe: "Oluwa mi, fun wi pe O ti se mi ni eni anu, dajudaju emi yoo se (aburu) ni oso fun won lori ile. Dajudaju emi yo si ko gbogbo won sinu anu |
afi awon erusin Re, awon eni esa ninu won |
(Allahu) so pe: "(Idurosinsin loju) ona taara, Owo Mi ni eyi wa |
إِنَّ عِبَادِي لَيْسَ لَكَ عَلَيْهِمْ سُلْطَانٌ إِلَّا مَنِ اتَّبَعَكَ مِنَ الْغَاوِينَ(42) Dajudaju awon erusin Mi, ko si agbara kan fun o lori won, ayafi eni ti o ba tele o ninu awon eni anu |
Ati pe dajudaju ina Jahanamo ni adehun fun gbogbo won |
لَهَا سَبْعَةُ أَبْوَابٍ لِّكُلِّ بَابٍ مِّنْهُمْ جُزْءٌ مَّقْسُومٌ(44) Awon oju ona meje n be fun (ina). Atunpin tun wa fun oju-ona kookan |
Dajudaju awon oluberu (Allahu) maa wa ninu awon Ogba Idera pelu awon odo (t’o n san nisale re) |
(A maa so pe): “E wo inu re pelu alaafia ni olufayabale.” |
وَنَزَعْنَا مَا فِي صُدُورِهِم مِّنْ غِلٍّ إِخْوَانًا عَلَىٰ سُرُرٍ مُّتَقَابِلِينَ(47) A si maa yo ohun ti n be ninu okan won t’o je inunibini kuro; (won yoo di) omo-iya (ara won. Won yoo wa) lori ibusun, ti won yoo koju sira won |
لَا يَمَسُّهُمْ فِيهَا نَصَبٌ وَمَا هُم مِّنْهَا بِمُخْرَجِينَ(48) Wahala kan ko nii ba won ninu re. Won ko si nii mu won jade kuro ninu re |
Fun awon erusin Mi ni iro pe dajudaju Emi ni Alaforijin, Asake-orun |
Ati pe dajudaju iya Mi ni iya eleta-elero |
Fun won ni iro nipa alejo (Anabi) ’Ibrohim |
إِذْ دَخَلُوا عَلَيْهِ فَقَالُوا سَلَامًا قَالَ إِنَّا مِنكُمْ وَجِلُونَ(52) (Ranti) nigba ti won wole to o, won si so pe: “Alaafia”. O so pe: “Dajudaju eru yin n ba awa.” |
قَالُوا لَا تَوْجَلْ إِنَّا نُبَشِّرُكَ بِغُلَامٍ عَلِيمٍ(53) Won so pe: "Ma se beru. Dajudaju awa yoo fun o ni iro idunnu (nipa bibi) omokunrin onimimo kan |
قَالَ أَبَشَّرْتُمُونِي عَلَىٰ أَن مَّسَّنِيَ الْكِبَرُ فَبِمَ تُبَشِّرُونَ(54) O so pe: "Se e n fun mi ni iro idunnu (nipa bibi omo) nigba ti ogbo ti de si mi? Iro idunnu wo ni e n fun mi na |
قَالُوا بَشَّرْنَاكَ بِالْحَقِّ فَلَا تَكُن مِّنَ الْقَانِطِينَ(55) Won so pe: “A n fun o ni iro idunnu pelu ododo. Nitori naa, ma se wa lara awon olujakanmuna.” |
قَالَ وَمَن يَقْنَطُ مِن رَّحْمَةِ رَبِّهِ إِلَّا الضَّالُّونَ(56) O so pe: “Ko ma si eni ti o maa jakanmuna ninu ike Oluwa Re bi ko se awon olusina.” |
O so pe: “Ki tun ni oro ti e ba wa, eyin Ojise?” |
Won so pe: "Dajudaju Won ran wa nise si ijo elese ni |
Afi ara ile (Anabi) Lut. Dajudaju awa yoo gba won la patapata |
إِلَّا امْرَأَتَهُ قَدَّرْنَا ۙ إِنَّهَا لَمِنَ الْغَابِرِينَ(60) Afi iyawo re; A ti ko kadara re (pe) dajudaju o maa wa ninu awon t’o maa seku leyin sinu iparun |
Nigba ti awon Ojise de odo ara ile (Anabi) Lut |
(Anabi Lut) so pe: “Dajudaju eyin je ajoji eniyan.” |
Won so pe: “Rara, a wa sodo re nitori ohun ti won n seyemeji nipa re |
A mu ododo wa ba o ni. Ati pe dajudaju olododo ni awa |
Nitori naa, mu ara ile re jade ni apa kan oru. Ki o si tele won leyin. Eni kan ninu yin ko si gbodo siju wo eyin wo. Ki e si lo si aye ti won n pa lase fun yin |
وَقَضَيْنَا إِلَيْهِ ذَٰلِكَ الْأَمْرَ أَنَّ دَابِرَ هَٰؤُلَاءِ مَقْطُوعٌ مُّصْبِحِينَ(66) A si je ki idajo oro yii han si i pe dajudaju A maa pa awon (elese) wonyi run patapata nigba ti won ba mojumo |
Awon ara ilu naa de, won si n yo sese |
(Anabi Lut) so pe: “Dajudaju awon wonyi ni alejo mi. Nitori naa, e ma se doju ti mi |
Ki e beru Allahu. Ki e si ma se yepere mi |
Won wi pe: “Nje awa ko ti ko fun o (nipa gbigba alejo) awon eda?” |
O so pe: “Awon omobinrin mi niwonyi, ti e ba ni nnkan ti e fe (fi won) se.” |
(Allahu so pe): “Mo fi isemi iwo (Anabi Muhammad) bura; dajudaju won kuku wa ninu idaamu opolo, ti won n pa ridarida.” |
Nitori naa, ohun igbe mu won nigba ti oorun owuro yo si won |
فَجَعَلْنَا عَالِيَهَا سَافِلَهَا وَأَمْطَرْنَا عَلَيْهِمْ حِجَارَةً مِّن سِجِّيلٍ(74) A si so oke ilu won di isale re (ilu won doju bole). A tun ro ojo okuta amo (sisun) le won lori |
Dajudaju awon ami wa ninu iyen fun awon alariiwoye |
Dajudaju (ilu naa) kuku wa loju ona (ti e n to lo to bo) |
Dajudaju ami wa ninu iyen fun awon onigbagbo ododo |
Awon ara ’Aekah naa je alabosi |
فَانتَقَمْنَا مِنْهُمْ وَإِنَّهُمَا لَبِإِمَامٍ مُّبِينٍ(79) A si gbesan lara won. Dajujaju awon ilu mejeeji l’o kuku wa loju ona gbangba (ti e n to lo to bo) |
Dajudaju awon ara Iho apata pe awon Ojise ni opuro |
A si fun won ni awon ami Wa. Amo won gbunri kuro nibe |
Won maa n gbe awon ile igbe ifayabale sinu awon apata |
Ohun igbe si mu won nigba ti won mojumo |
Ohun ti won n se nise ko si ro won loro (nibi iya) |
A ko seda awon sanmo, ile ati nnkan t’o wa laaarin awon mejeeji bi ko se pelu ododo. Dajudaju Akoko naa maa de. Nitori naa, samojukuro ni amojukuro t’o rewa |
Dajudaju Oluwa re ni Eledaa, Onimo |
وَلَقَدْ آتَيْنَاكَ سَبْعًا مِّنَ الْمَثَانِي وَالْقُرْآنَ الْعَظِيمَ(87) Dajudaju A fun o ni Sab‘u Mothani (iyen, surah al-Fatihah) ati al-Ƙur’an t’o tobi |
Iwo ko gbodo siju re wo ohun ti A fi se igbadun aye lorisirisi fun awon kan ninu won. Ma se banuje nitori won. Ki o si re apa re nile fun awon onigbagbo ododo |
Ki o si so pe: “Dajudaju emi ni olukilo ponnbele.” |
Gege bi A se so (iya) kale fun awon t’o n pin ododo mo iro |
awon ti won so al-Ƙur’an di ipinkupin-in |
Oluwa re fi Ara Re bura fun o pe, A maa bi gbogbo won ni ibeere |
nipa ohun ti won n se nise |
Nitori naa, kede nnkan ti A pa lase fun o. Ki o si seri kuro lodo awon osebo |
Dajudaju Awa yoo to o (nibi aburu) awon oniyeye |
الَّذِينَ يَجْعَلُونَ مَعَ اللَّهِ إِلَٰهًا آخَرَ ۚ فَسَوْفَ يَعْلَمُونَ(96) awon t’o n mu olohun miiran mo Allahu. Laipe won maa mo |
وَلَقَدْ نَعْلَمُ أَنَّكَ يَضِيقُ صَدْرُكَ بِمَا يَقُولُونَ(97) Awa kuku ti mo pe dajudaju ohun ti won n wi n ko inira ba o |
Nitori naa, se afomo pelu idupe fun Oluwa re. Ki o si wa ninu awon oluforikanle (fun Un) |
Josin fun Oluwa re titi amodaju (iyen, iku) yoo fi de ba o |
Plus de sourates en Yoruba :
Téléchargez la sourate avec la voix des récitants du Coran les plus célèbres :
Téléchargez le fichier mp3 de la sourate Al-Hijr : choisissez le récitateur pour écouter et télécharger la sourate Al-Hijr complète en haute qualité.















Donnez-nous une invitation valide