Surah Al-Bayyinah ni Arabic ati Yorùbá
Ka Surah Al-Bayyinah pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (8 Ẹsẹ — مدنية). Al-Bayyinah Gbọ, Al-Bayyinah Itumọ, Al-Bayyinah mp3, Al-Bayyinah pdf.Ka ati Gbọ Surah Al-Bayyinah
🎧 Ẹsẹ
M
Mishary Rashid Alafasy
✓
Mishary Rashid Alafasy
✓
M
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
A
Abdurrahman As-Sudais
✓
Abdurrahman As-Sudais
✓
M
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
A
Abdul Basit Abdul Samad
✓
Abdul Basit Abdul Samad
✓
A
Ali Al-Hudhaify
✓
Ali Al-Hudhaify
✓
A
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
A
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
M
Muhammad Ayyoub
✓
Muhammad Ayyoub
✓
A
Abdullah Basfar
✓
Abdullah Basfar
✓
A
Abdullah Al-Juhani
✓
Abdullah Al-Juhani
✓
M
Maher Al Muaiqly
✓
Maher Al Muaiqly
✓
—
x1
لَمْ يَكُنِ الَّذِينَ كَفَرُوا مِنْ أَهْلِ الْكِتَابِ وَالْمُشْرِكِينَ مُنفَكِّينَ حَتَّىٰ تَأْتِيَهُمُ الْبَيِّنَةُ ١
📖 Itumọ
Ẹsẹ 1
Awon t’o sai gbagbo ninu awon ahlul-kitab ati awon osebo, won ko nii kuro ninu aigbagbo won titi di igba ti eri t’o yanju yo fi maa de odo won
رَسُولٌ مِّنَ اللَّهِ يَتْلُو صُحُفًا مُّطَهَّرَةً ٢
📖 Itumọ
Ẹsẹ 2
Ojise kan lati odo Allahu yo (si) maa ke awon takada mimo
وَمَا تَفَرَّقَ الَّذِينَ أُوتُوا الْكِتَابَ إِلَّا مِن بَعْدِ مَا جَاءَتْهُمُ الْبَيِّنَةُ ٤
📖 Itumọ
Ẹsẹ 4
Awon ti A fun ni tira ko si di ijo otooto afi leyin ti eri t’o yanju de ba won
وَمَا أُمِرُوا إِلَّا لِيَعْبُدُوا اللَّهَ مُخْلِصِينَ لَهُ الدِّينَ حُنَفَاءَ وَيُقِيمُوا الصَّلَاةَ وَيُؤْتُوا الزَّكَاةَ ۚ وَذَٰلِكَ دِينُ الْقَيِّمَةِ ٥
📖 Itumọ
Ẹsẹ 5
Awa ko si pa won ni ase kan bi ko se pe ki won josin fun Allahu (ki won je) oluse-afomo esin fun Un, oluduro deede. Ki won kirun, ki won si yo Zakah. Iyen si ni esin t’o fese rinle
إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا مِنْ أَهْلِ الْكِتَابِ وَالْمُشْرِكِينَ فِي نَارِ جَهَنَّمَ خَالِدِينَ فِيهَا ۚ أُولَٰئِكَ هُمْ شَرُّ الْبَرِيَّةِ ٦
📖 Itumọ
Ẹsẹ 6
Dajudaju awon t’o sai gbagbo (wonyi) ninu awon ahlul-kitab ati awon osebo, won yoo wa ninu Ina. Olusegbere ni won ninu re. Awon wonyen, awon ni eda t’o buru julo
إِنَّ الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ أُولَٰئِكَ هُمْ خَيْرُ الْبَرِيَّةِ ٧
📖 Itumọ
Ẹsẹ 7
Dajudaju awon t’o gbagbo ni ododo (iyen, awon musulumi), ti won si se awon ise rere, awon wonyen, awon ni eda t’o dara julo
جَزَاؤُهُمْ عِندَ رَبِّهِمْ جَنَّاتُ عَدْنٍ تَجْرِي مِن تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا أَبَدًا ۖ رَّضِيَ اللَّهُ عَنْهُمْ وَرَضُوا عَنْهُ ۚ ذَٰلِكَ لِمَنْ خَشِيَ رَبَّهُ ٨
📖 Itumọ
Ẹsẹ 8
Esan won ni odo Oluwa won ni awon Ogba Idera gbere, ti awon odo n san ni isale re. Olusegbere ni won ninu re titi laelae. Allahu yonu si won. Awon naa yonu si (ohun ti Allahu fun won). Iyen wa fun enikeni ti o ba paya Oluwa re
Kika Surah Al-Bayyinah ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers

