Surah Ad-Duha ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Ad-Duha pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (11 Ẹsẹ — مكية). Ad-Duha Gbọ, Ad-Duha Itumọ, Ad-Duha mp3, Ad-Duha pdf.

Ka ati Gbọ Surah Ad-Duha

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy
M Mahmoud Khalil Al-Husary
A Abdurrahman As-Sudais
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi
A Abdul Basit Abdul Samad
A Ali Al-Hudhaify
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy
A Abu Bakr Ash-Shaatree
M Muhammad Ayyoub
A Abdullah Basfar
A Abdullah Al-Juhani
M Maher Al Muaiqly
x1
وَالضُّحَىٰ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
(Allahu bura pelu) iyaleta
وَاللَّيْلِ إِذَا سَجَىٰ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
O tun bura pelu ale nigba ti (ile) ba su
مَا وَدَّعَكَ رَبُّكَ وَمَا قَلَىٰ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
Oluwa re ko pa o ti, ko si binu si o
وَلَلْآخِرَةُ خَيْرٌ لَّكَ مِنَ الْأُولَىٰ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
Dajudaju orun loore fun o ju aye lo
وَلَسَوْفَ يُعْطِيكَ رَبُّكَ فَتَرْضَىٰ ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
Dajudaju laipe Oluwa re maa fun o ni (oore pupo ni orun). Nitori naa, o si maa yonu si i
أَلَمْ يَجِدْكَ يَتِيمًا فَآوَىٰ ۝٦
📖 Itumọ Ẹsẹ 6
Se (Allahu) ko ri o ni omo-orukan ni? O si fun o ni ibugbe
وَوَجَدَكَ ضَالًّا فَهَدَىٰ ۝٧
📖 Itumọ Ẹsẹ 7
O si ri o ni alaimona (iyen siwaju isokale imisi). O si fi ona mo o
وَوَجَدَكَ عَائِلًا فَأَغْنَىٰ ۝٨
📖 Itumọ Ẹsẹ 8
O tun ri o ni alaini, O si ro o loro
فَأَمَّا الْيَتِيمَ فَلَا تَقْهَرْ ۝٩
📖 Itumọ Ẹsẹ 9
Nitori naa, ni ti omo-orukan, ma se je gaba (le e lori)
وَأَمَّا السَّائِلَ فَلَا تَنْهَرْ ۝١٠
📖 Itumọ Ẹsẹ 10
Ni ti alagbe, ma si se jagbe (mo on)
وَأَمَّا بِنِعْمَةِ رَبِّكَ فَحَدِّثْ ۝١١
📖 Itumọ Ẹsẹ 11
Ni ti idera Oluwa re, so o jade
← 92 Ad-Duha (93/114) 94 →
Kika Surah Ad-Duha ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

93الضحى Ad-Duha 📚 11 Ẹsẹ مكية

Ẹsẹ kọọkan – Surah Ad-Duha — 11 Ẹsẹ




Al-Kur'an


Tuesday, August 18, 2026

Don't forget us in your sincere prayers