Surah Al-Qadr ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-Qadr pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (5 Ẹsẹ — مكية). Al-Qadr Gbọ, Al-Qadr Itumọ, Al-Qadr mp3, Al-Qadr pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-Qadr

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
—
x1
bismillah
إِنَّا أَنزَلْنَاهُ فِي لَيْلَةِ الْقَدْرِ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Dajudaju Awa so al-Ƙur’an kale ninu Oru Abiyi
وَمَا أَدْرَاكَ مَا لَيْلَةُ الْقَدْرِ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Oru Abiyi
لَيْلَةُ الْقَدْرِ خَيْرٌ مِّنْ أَلْفِ شَهْرٍ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
Oru Abiyi loore ju egberun osu lo
تَنَزَّلُ الْمَلَائِكَةُ وَالرُّوحُ فِيهَا بِإِذْنِ رَبِّهِم مِّن كُلِّ أَمْرٍ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
Awon molaika ati Jibril yo si maa sokale ninu oru naa pelu ase Oluwa won fun gbogbo oro eda kookan
سَلَامٌ هِيَ حَتَّىٰ مَطْلَعِ الْفَجْرِ ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
Alaafia ni oru naa titi di asiko afemojumo
← 96 Al-Qadr (97/114) 98 →
Kika Surah Al-Qadr ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

97القدر Al-Qadr 📚 5 Ẹsẹ مكية



Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers