Surah Al-Fatihah ni Arabic ati Yorùbá
Ka Surah Al-Fatihah pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (7 Ẹsẹ — مكية). Al-Fatihah Gbọ, Al-Fatihah Itumọ, Al-Fatihah mp3, Al-Fatihah pdf.Ka ati Gbọ Surah Al-Fatihah
🎧 Ẹsẹ
M
Mishary Rashid Alafasy
✓
Mishary Rashid Alafasy
✓
M
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
A
Abdurrahman As-Sudais
✓
Abdurrahman As-Sudais
✓
M
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
A
Abdul Basit Abdul Samad
✓
Abdul Basit Abdul Samad
✓
A
Ali Al-Hudhaify
✓
Ali Al-Hudhaify
✓
A
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
A
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
M
Muhammad Ayyoub
✓
Muhammad Ayyoub
✓
A
Abdullah Basfar
✓
Abdullah Basfar
✓
A
Abdullah Al-Juhani
✓
Abdullah Al-Juhani
✓
M
Maher Al Muaiqly
✓
Maher Al Muaiqly
✓
—
x1
إِيَّاكَ نَعْبُدُ وَإِيَّاكَ نَسْتَعِينُ ٥
📖 Itumọ
Ẹsẹ 5
Iwo nikan ni a n josin fun. Odo Re nikan si ni a n wa oore si
اهْدِنَا الصِّرَاطَ الْمُسْتَقِيمَ ٦
📖 Itumọ
Ẹsẹ 6
Jijosin fun Allahu nikan soso ati diduro sinsin ninu ijosin Re itumo yii wa bee ninu surah Ali ‘Imron “Fi ese wa rinle sinu ’Islam ona taara.” Nitori naa
صِرَاطَ الَّذِينَ أَنْعَمْتَ عَلَيْهِمْ غَيْرِ الْمَغْضُوبِ عَلَيْهِمْ وَلَا الضَّالِّينَ ٧
📖 Itumọ
Ẹsẹ 7
ona awon ti O se idera fun,yato si (ona) awon eni-ibinu (iyen, awon yehudi) ati (ona) awon olusina (iyen, awon nasara)
Al-Fatihah (1/114)
2 →
Kika Surah Al-Fatihah ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers

