Surah Al-Falaq ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-Falaq pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (5 Ẹsẹ — مكية). Al-Falaq Gbọ, Al-Falaq Itumọ, Al-Falaq mp3, Al-Falaq pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-Falaq

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
—
x1
bismillah
قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ الْفَلَقِ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
So pe: "Mo sa di Oluwa owuro kutukutu
مِن شَرِّ مَا خَلَقَ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
nibi aburu ohun ti O da
وَمِن شَرِّ غَاسِقٍ إِذَا وَقَبَ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
ati nibi aburu oru nigba ti o ba sookun
وَمِن شَرِّ النَّفَّاثَاتِ فِي الْعُقَدِ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
ati nibi aburu awon (opidan) t’o n fenu fategun tuetue sinu awon onde
وَمِن شَرِّ حَاسِدٍ إِذَا حَسَدَ ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
ati nibi aburu onilara nigba ti o ba se ilara
← 112 Al-Falaq (113/114) 114 →
Kika Surah Al-Falaq ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

113الفلق Al-Falaq 📚 5 Ẹsẹ مكية



Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers