Surah An-Nas ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah An-Nas pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (6 Ẹsẹ — مكية). An-Nas Gbọ, An-Nas Itumọ, An-Nas mp3, An-Nas pdf.

Ka ati Gbọ Surah An-Nas

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
—
x1
bismillah
قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ النَّاسِ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
So pe: "Mo sa di Oluwa awon eniyan
مَلِكِ النَّاسِ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
Oba awon eniyan
إِلَٰهِ النَّاسِ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
Olohun awon eniyan
مِن شَرِّ الْوَسْوَاسِ الْخَنَّاسِ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
nibi aburu (Esu) oniroyiroyi, olusaseyin (fun eni t’o ba daruko Allah)
الَّذِي يُوَسْوِسُ فِي صُدُورِ النَّاسِ ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
(Esu ni) eni ti o n ko royiroyi sinu awon okan eniyan
مِنَ الْجِنَّةِ وَالنَّاسِ ۝٦
📖 Itumọ Ẹsẹ 6
(Esu naa) wa ninu alujannu ati eniyan
← 113 An-Nas (114/114)
Kika Surah An-Nas ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

114الناس An-Nas 📚 6 Ẹsẹ مكية



Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers