Surah Al-Ikhlas ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-Ikhlas pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (4 Ẹsẹ — مكية). Al-Ikhlas Gbọ, Al-Ikhlas Itumọ, Al-Ikhlas mp3, Al-Ikhlas pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-Ikhlas

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
—
x1
bismillah
قُلْ هُوَ اللَّهُ أَحَدٌ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
So pe: "Oun ni Allahu, Okan soso
اللَّهُ الصَّمَدُ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
Allahu ni Asiwaju (ti eda ni bukata si, ti Oun ko si ni bukata si won)
لَمْ يَلِدْ وَلَمْ يُولَدْ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
Ko bimo. Won ko si bi I
وَلَمْ يَكُن لَّهُ كُفُوًا أَحَدٌ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
Ko si si eni kan ti o jo O." eyi ni a mo si “robbu-ssamowat wal-’ard wa mo baenahumo”. Idi niyi ti a o fi tumo “Allahu” si “Olohun”. Ninu ede Yoruba ko fee si itumo ti a fokan bale si fun oro-oruko nla naa “Allahu” afi lilo oro-oruko kan eyi ti awon Yoruba maa n lo ni ojoun ana fun “Olohun”. Sise bee si maa mu ariyanjiyan lowo. Nitori naa
← 111 Al-Ikhlas (112/114) 113 →
Kika Surah Al-Ikhlas ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

112الإخلاص Al-Ikhlas 📚 4 Ẹsẹ مكية



Al-Kur'an


Thursday, October 1, 2026

Don't forget us in your sincere prayers