Surah Az-Zalzalah ni Arabic ati Yorùbá
Ka Surah Az-Zalzalah pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (8 Ẹsẹ — مدنية). Az-Zalzalah Gbọ, Az-Zalzalah Itumọ, Az-Zalzalah mp3, Az-Zalzalah pdf.Ka ati Gbọ Surah Az-Zalzalah
🎧 Ẹsẹ
M
Mishary Rashid Alafasy
✓
Mishary Rashid Alafasy
✓
M
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
Mahmoud Khalil Al-Husary
✓
A
Abdurrahman As-Sudais
✓
Abdurrahman As-Sudais
✓
M
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
Mohamed Siddiq Al-Minshawi
✓
A
Abdul Basit Abdul Samad
✓
Abdul Basit Abdul Samad
✓
A
Ali Al-Hudhaify
✓
Ali Al-Hudhaify
✓
A
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
Ahmed ibn Ali al-Ajamy
✓
A
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
Abu Bakr Ash-Shaatree
✓
M
Muhammad Ayyoub
✓
Muhammad Ayyoub
✓
A
Abdullah Basfar
✓
Abdullah Basfar
✓
A
Abdullah Al-Juhani
✓
Abdullah Al-Juhani
✓
M
Maher Al Muaiqly
✓
Maher Al Muaiqly
✓
—
x1
وَأَخْرَجَتِ الْأَرْضُ أَثْقَالَهَا ٢
📖 Itumọ
Ẹsẹ 2
ati (nigba) ti ile ba tu awon eru t’o wuwo ninu re jade
يَوْمَئِذٍ تُحَدِّثُ أَخْبَارَهَا ٤
📖 Itumọ
Ẹsẹ 4
Ni ojo yen ni (ile) yoo soro nipa awon iro re (ti eda gbe ori ile se)
بِأَنَّ رَبَّكَ أَوْحَىٰ لَهَا ٥
📖 Itumọ
Ẹsẹ 5
Nitori pe dajudaju Oluwa re l’O fun un ni ase (lati soro)
يَوْمَئِذٍ يَصْدُرُ النَّاسُ أَشْتَاتًا لِّيُرَوْا أَعْمَالَهُمْ ٦
📖 Itumọ
Ẹsẹ 6
Ni ojo yen, awon eniyan yoo maa gba ona otooto lo nitori ki won le fi awon ise won han won
فَمَن يَعْمَلْ مِثْقَالَ ذَرَّةٍ خَيْرًا يَرَهُ ٧
📖 Itumọ
Ẹsẹ 7
Nitori naa, eni ti o ba se ise rere ni odiwon omo ina-igun, o maa ri i
وَمَن يَعْمَلْ مِثْقَالَ ذَرَّةٍ شَرًّا يَرَهُ ٨
📖 Itumọ
Ẹsẹ 8
Eni ti o ba si se ise aburu ni odiwon omo ina-igun, o maa ri i
Kika Surah Az-Zalzalah ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun
Al-Kur'an
Tuesday, August 18, 2026
Don't forget us in your sincere prayers

