Surah An-Nasr ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah An-Nasr pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (3 Ẹsẹ — مدنية). An-Nasr Gbọ, An-Nasr Itumọ, An-Nasr mp3, An-Nasr pdf.

Ka ati Gbọ Surah An-Nasr

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
—
x1
bismillah
إِذَا جَاءَ نَصْرُ اللَّهِ وَالْفَتْحُ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Nigba ti aranse Allahu (lori ota esin) ati sisi ilu (Mokkah) ba sele
وَرَأَيْتَ النَّاسَ يَدْخُلُونَ فِي دِينِ اللَّهِ أَفْوَاجًا ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
ti o si ri awon eniyan ti won wonu esin Allahu nijonijo
فَسَبِّحْ بِحَمْدِ رَبِّكَ وَاسْتَغْفِرْهُ ۚ إِنَّهُ كَانَ تَوَّابًا ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
nitori naa, safomo pelu idupe fun Oluwa re. Ki o si toro aforijin lodo Re. Dajudaju O n je Olugba-ironupiwada
← 109 An-Nasr (110/114) 111 →
Kika Surah An-Nasr ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

110النصر An-Nasr 📚 3 Ẹsẹ مدنية



Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers