Surah An-Nasr pdf — Gbà (Yorùbá)
Surah An-Nasr pdf Yorùbá — Gbà Surah An-Nasr Itumọ. Surah An-Nasr (Medinan) 3 Ẹsẹ.
Related
- Surah An-Nasr ItumọYorùbá
- Surah An-Nasr mp3Gbọ
- Quran Index Yorùbá114
More Surah PDF
Surah An-Nasr

ﭱﭲﭳﭴﭵﭶ
110:1
Nigba ti aranse Allahu (lori ota esin) ati sisi ilu (Mokkah) ba sele
ﭷﭸﭹﭺﭻﭼﭽﭾ
110:2
ti o si ri awon eniyan ti won wonu esin Allahu nijonijo
ﭿﮀﮁﮂﮃﮄﮅﮆﮇ
110:3
nitori naa, safomo pelu idupe fun Oluwa re. Ki o si toro aforijin lodo Re. Dajudaju O n je Olugba-ironupiwada
Al-Kur'an
Wednesday, September 9, 2026
Don't forget us in your sincere prayers







