Surah Al-Masad ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Al-Masad pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (5 Ẹsẹ — مكية). Al-Masad Gbọ, Al-Masad Itumọ, Al-Masad mp3, Al-Masad pdf.

Ka ati Gbọ Surah Al-Masad

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
—
x1
bismillah
تَبَّتْ يَدَا أَبِي لَهَبٍ وَتَبَّ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
Owo Abu-Lahab mejeeji ti sofo. Oun naa si sofo
مَا أَغْنَىٰ عَنْهُ مَالُهُ وَمَا كَسَبَ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
Awon dukia re ati ohun ti o se nise (iyen, awon omo re) ko si nii ro o loro (nibi iya)
سَيَصْلَىٰ نَارًا ذَاتَ لَهَبٍ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
O si maa wo inu Ina elejo fofo
وَامْرَأَتُهُ حَمَّالَةَ الْحَطَبِ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
Ati iyawo re, alaaaru-igi-isepe elegun-un, (o maa wona)
فِي جِيدِهَا حَبْلٌ مِّن مَّسَدٍ ۝٥
📖 Itumọ Ẹsẹ 5
Igba-ope ponponran maa wa ni orun re (ninu Ina)
← 110 Al-Masad (111/114) 112 →
Kika Surah Al-Masad ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

111المسد Al-Masad 📚 5 Ẹsẹ مكية



Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers