Surah Quraysh ni Arabic ati Yorùbá

Ka Surah Quraysh pẹlu itumọ pipe ni Yorùbá ati iṣẹ́-ohun. Itumọ ẹsẹ kọọkan. (4 Ẹsẹ — مكية). Quraysh Gbọ, Quraysh Itumọ, Quraysh mp3, Quraysh pdf.

Ka ati Gbọ Surah Quraysh

🎧 Ẹsẹ
M Mishary Rashid Alafasy ✓
M Mahmoud Khalil Al-Husary ✓
A Abdurrahman As-Sudais ✓
M Mohamed Siddiq Al-Minshawi ✓
A Abdul Basit Abdul Samad ✓
A Ali Al-Hudhaify ✓
A Ahmed ibn Ali al-Ajamy ✓
A Abu Bakr Ash-Shaatree ✓
M Muhammad Ayyoub ✓
A Abdullah Basfar ✓
A Abdullah Al-Juhani ✓
M Maher Al Muaiqly ✓
—
x1
bismillah
لِإِيلَافِ قُرَيْشٍ ۝١
📖 Itumọ Ẹsẹ 1
(Ike ni lati odo Allahu) fun idile Ƙuraes lati wa papo ninu aabo
إِيلَافِهِمْ رِحْلَةَ الشِّتَاءِ وَالصَّيْفِ ۝٢
📖 Itumọ Ẹsẹ 2
(Ike ni se lati odo Allahu) fun won lati wa papo ninu aabo lori irin-ajo ni igba otutu ati igba ooru
فَلْيَعْبُدُوا رَبَّ هَٰذَا الْبَيْتِ ۝٣
📖 Itumọ Ẹsẹ 3
Nitori naa, ki won josin fun Oluwa Ile (Ka‘bah) yii
الَّذِي أَطْعَمَهُم مِّن جُوعٍ وَآمَنَهُم مِّنْ خَوْفٍ ۝٤
📖 Itumọ Ẹsẹ 4
Eni ti O fun won ni jije (ni asiko) ebi. O si fi won lokan bale ninu ipaya
← 105 Quraysh (106/114) 107 →
Kika Surah Quraysh ni Yorùbá – Itumọ ati Ohun

106قريش Quraysh 📚 4 Ẹsẹ مكية



Al-Kur'an


Monday, September 28, 2026

Don't forget us in your sincere prayers